AGBARA JAZZ Lyrics
- Genre:Jazz
- Year of Release:2022
Lyrics
Shedrack
Meshach
Abednego
Daniel
Lazarus
Abednego
Agbara to ja fun won wa laye
Agbara to ja fun won wa laye
To ba ti ni igba gbo a ma ja fun o
Ti n ba ti ni igba gbo a ma ja fun mi
This life there are tribulation
Jesus told us in the bible
Jowo ma she se pe o be ru ra ra
Fi igba gbo re si nu Jesu ko le gbe gba ope
Shedrack
Meshach
Abednego
Daniel
Lazarus
Abednego
Agbara to ja fun won wa laye
Agbara to ja fun won wa laye
To ba ti ni igba gbo a ma ja fun re
Ti n ba ti ni igba gbo a ma ja fun mi
There is power in the name of Jesus
Agbara to ji oku di de ma lo je
Don't you ever forget when you pray
Igba gbo re ni nu oluwa le ran re lowo
Shedrack
Meshach
Abednego
Daniel
Lazarus
Abednego
Agbara to ja fun won wa laye
Agbara to ja fun won wa laye
Ti n ba ti ni igba gbo a ma ja fun mi
To ba ti ni igba gbo a ma ja fun re