
Alagbawi Eda (The Advocate) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Alagbawi Eda (The Advocate) - Bose David
...
Arugbo aye eeee
Ijinle to ju ijinle lo
Oba awon oba
King of glory
Elese anu eleru niyin oba
oba mi,jowo o,sanu funmi
Chorus:
Oso aye mi dotun
Gbani gbani lojo isoro
Ol'owo anu oloju anu
Arugbo to ga (2ce)
Oso ninu iwe mimo
Pe ohun yio sanu, feni to hun,
yio sanu fun,ol'oju anu
Alagbawi Eda
Chorus:
Oso aye mi dotun
Gbani gbani l'ojo isoro
Ol'owo anu ol'oju anu
Arugbo to ga (2ce)
Repeat solo
Arugbo aye eeee
Ijinle to ju ijinle lo
Oba awon oba
King of glory
Elese anu eleru n'yin oba
oba mi,jowo o sanu funmi
Repeat chorus
Bridge : Alagbawi eda o (4ce)
(God's Praises)
Imo ninu imo
Oye ninu oye
Adani ma gbagbe eni
Adani ma daa ni
Odami ko da mi
Olorun ajobo
Emi to ni emi eniyan lowo
Aso be jebe sebe
Asoro mata se
O gbeni nija,keru ba'nija
Eleti gbohun gbo aroye eee
Alagbawi eda