Mo Wa Dupe Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Oun ti Baba se, o jo mi l'oju
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Iyin at'ope lo ye Baba
Ogo ye o, Oba ayeraye
Ope mi re o, Atobajaye
Egberun ahan o, ko to yin Baba
Ma f'aye t'E fun mi, ma fi gbe O ga o
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Oun ti Baba se, o jo mi l'oju
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Iyin at'ope lo ye Baba
Erujeje to so 'le aye ro
Alewilese
Oyigiyigi, Atofarati
Gb'Aleluya mi
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Oun ti Baba se, o jo mi l'oju
Mo wa dupe
Mo m'ope mi wa o
Iyin at'ope lo ye Baba
Iyin at'ope lo ye Baba
Iyin at'ope lo ye Baba