![This Is My Lagos](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/47/47/rBEeMVme50WAPElSAAEB2mt141I386.jpg)
This Is My Lagos Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2017
Lyrics
(Talking drum)
Ekajue!
Bawo kaju ilu, yiya lo'nya
Ekajue!
This is my Lagos x3
Eko ooo... aromisa legbe legbe
This is my Lagos
Ilu ti baba gbe kale so ri omi
Alagbalugbu omi okun
Alagbalugbu omi osa
Hausa de be o ri se
Igbo de be o ri se
Yoruba de be won je lo
Awon foreigners lorishirishi
Won de be won ri se
This is my Lagos X3
Eye maa sope owo eko, eko lo'ungbe
Ede ye ma sope owo eko, eko lo'ungbe
United state of Nigeria
Sa ni Lagos se raye e
Irawo Eko, ko ni wo inu okun o
Osupa e, koni wo ***
Iba Oluhun oba, iba eniyan
Oba Oluwa ma se b'Eko je fun wa o
This is my Lagos X4
Eko mo nlo odede lori omi
Aleko mo nlo odede lori omi o
Mori Baba meta mokere
Mo nse goodu morning sir
Mo ba nki won
As I am welcome to Lagos
Mo nberi fun won
Alaso funfun meta
Islanders! Mi o je ko yan yi kere
Gbogbo omo eko mi o je ko yan yi kere
Eyan to ko yan omo Eko kere
Onitohun aje iyan e l'ewura o
Onitohun aje iyan e l'ewura o
Eko mi, Eko e, Eko to daaju
Odara, olewa, odara pupo o
Kosi ibi kibi ti mo lewa lori ile aiye
Ti mo le gbagbe Eko akete
Eko mi, Eko e, Eko to daaju
Odara, olewa, odara pupo o
Kosi ibi kibi ti mo lewa lori ile aiye
Ti mo le gbagbe Eko akete
Eko aromisa legbe legbe
Aromisa legbe legbe
Eko l'eleja tutu, eyin le leja obokun
Eyin le l'akon, akon to gb'ata anu o
Ah! Itesiwaju Eko lafe!
This is my Lagos
Eko oni ko e lo
This is my Lagos
Ah Eko oni ko mi lo
This is my Lagos
Ko si ounje fun ole leko
This is my Lagos
Ohun gangan ni center of excellent
This is my Lagos
Eyin omo Eko e ma ya ole e
This is my Lagos
Ki atepa owo mo se pada o
This is my Lagos
Ki ama se so le o
This is my Lagos
Ole oda fun eni keni mo so
This is my Lagos
Gbogbo wa sa la leko
This is my Lagos