IBA RE Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
IBA RE - Testimony Jaga
...
Hmmmm
Thank you Jesus
Eranko wan Jubare ……
Eja inu ibu won jubare ……
Gbogbo eye ton do loke eye eye won jubare
Kilowasemi naa ti mio ni jubare
Kilo se e na to o ni Juba baba
A jubare aaa jubare …….
Olorun iyanu …….
A jubare
Iyanu Loro e
Oro Re iyanu ni
Iseowo Re iyanu
Bose da aya iyanu ni
Iwa Re iyanu ni
Be sen se iyanu ni
Oba iyanu ti so aye mi di iyanu
Oba a Lase
Oba to pa se fun ojo ko jo
Oba tin pase fun Orun ko tan
Oba ton pase fun ale ko le
Oba to tin ba Lori oungbogbo
Oba to ba Lori oun gbogbo
Oba to fi wa joba Lori oun gbogbo
Oba oungbogbo
You are the God of heaven and the earth
The beginning and the end
God of ever try
Strong and blessed one
That is who you are babami
Ibare……….
Iba. Akoda iba aseda
Iba olorun to po ni ipa ati agbare
Emi awon Christiani
Oba to gbe iku mi ni isegun
Oba ta le le le ta o le ba
Oba ti o need Lati Leni ko to bani
Alabe nu ansasi onile asawo
Olowo gbani gbani
Atuni gbe atuni mo
Ataye e ni se
Oloju ni le oloju lajo
Babami tin ri oungbogbo to mo oun gbogbo
Ton se oungbogbo ni gba gbogbo
Oba igba gbogbo…..