Ololade Commonwealth Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2022
Lyrics
Ololade Commonwealth - Taiwo Omotunde
...
TariqAyan kojo o Ololade
OmO Lamidi mi o Common wealth
Tariq Ayan Kojo o Ololade
Omo Lamidi Mi o Commonwealth
Eketa Ola ku Fo Ni ibadan gentlemen
Apesin Ola Ololade
Eketa Ola ku Fo Ni Ibadan Gentlemen
Apesin Ola Ololade
Alase Commonwealth Home and Investment limited
Ibadan Mesi Ogor Ni Ile Oluyole
OmO A Je Mi Fi ka Ara Ohun Fo rimu
Tariq Ayankojor
Ololade Mo Ba Rode Oshey
Ma Gbadun Ni Ti E Baba Oloye Pupo
Maa Lo Si Waju
Maa Te Siwaju
KILETIWI
Tariq Ayankojo Ololade
Omo Lamidi Mi O Commonwealth
Tariq Ayankojo Ololade
OmO Lamidi Mi O Commonwealth
Eketa Ola ku Fo Ni Ibadan Gentlemen
Apesin Ola Ololade
Apesin Ola ni
Eketa Ola Ku Fo Ni Ibadan Gentlemen
Apesin Ola Ololade
International Business Men
Otepa Moshey Lati Kekere O Jare
Edumare Lo Gbe E De Ipo Ola Ololade
Nigba ti o Wi ki Tenikan Maa Daa o
Olorire Alhaji Chief Ololade
Ke Bami ki
Tariq Ayankojo o Ololade
OmO Lamidi Mi o Commonwealth
Tariq Ayankojo o Ololade
OmO Lamidi Mi o Commonwealth
Eketa Ola ku Fo Ni Ibadan Gentlemen
Apesin Ola Ololade .......
Ibadan Ni Won Bi E Si
Ibadan Ni Won Bi E Si o
Baba Re Pelu Won Lo Ni Ile
Baba Re Pelu Won Lo Ni Ile
Ni Ibadan o o o Aye
Ni Ibadan Ni Won Bi E Si
Ololade
O Gbo Bi Yoruba Tin Wi ?
Gbo Bi Yoruba Tin Wi o
O Gbo Bi Yoruba Tin soro ?
Gbo Bi Yoruba Tin Wi o
Ololade
Oke Ni Owo Afuni Gbe
Iwaju Lowo Aja N Lo
Oke Lemu Ru Si O
kilewi
Oke Ni Owo Afuni Gbe
Iwaju Lowo Aja N Lo
Oke Ni Emu Ru Si o
O Gbo Bi Yoruba Tin Soro
Gbo Bi Yoruba Tin Wi o
Oke Lowo Afuni Ngbe
Iwaju Lowo Aja N Lo
Oke Lemu Ru si o
Oke lowo Afuni Ngbe
Iwaju lowo Aja n Lo
Oke Lemu Ru Si o
Tariq Lo Tale Ati Mo
Commonwealth Lo n Tale Re
ololade
Ololade Lo Tale Ati mo
Commonwealth Lo N Tale Re
alashe commonwealth
Tariq Lon Tale Ati Mo
home and investment ltd
Commonwealth Lo Tale Re
eketa aldugbo ni ibadan
Ololade Lon Tale Ati Mo
apesin ola ololade
Commonwealth Lon Tale Re
maa gbadun ni ti e
Tariq lon tale ati mo
Mo Ba Rode