Asiko mi to (It's my time) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Orun si
Nitori mi
Orun si o
Nitori aye mi
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere ( 2ce)
It's my time to shine
Nothing will stop it
I am meant for greatness
I am meant for upliftment
Because my appointed time is now
Asiko mi to
My set time is now
Asiko mi ti to
My appointed time is now
Asiko mi to
My set time is now
Asiko mi ti to
Orun si
Nitori mi
Orun si o
Nitori aye mi
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Whether devil like it or not
I will be celebrated this year
For I have been called out of darkness into God's marvellous light
I've been made a king unto my God to reign on earth
The glory of God has risen upon me
Orun si
Nitori mi
Orun si o
Nitori aye mi
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
I confess, declare, announce
Asiko mi to
Asiko igbedide, ise logo
Asiko mi ti to
Asiko orire, igbega
Otito
Je ka araye bami gbe gba ope
Orun si
Nitori mi
Orun si o
Nitori aye mi
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Si iwe iranti kan mi
Asiko mi to lati se rere
Call: Asiko mi to lati la lati se aseyori
Res: Asiko mi to lati tan lati se aseyori
Call: Asiko mi to lati tan lati se rere laaye
Resp: Asiko mi to lati la lati se aseyori
Call: My time has come, my time is now, Asiko mi to
Resp: Asiko mi to lati tan lati se aseyori
Call: our time has come, our time is now,Asiko wa to
Resp: Asiko mi to lati la lati se aseyori