OJO IBUKUN Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
(Ojo ibukun maa ro sori mi)
Ase Oluwa ni
(Ojo ibukun ma ro si' le mi)
Ase Oluwa ni
(Heee) (Maro maro) Maro,maro maro sori mi
Maro (Saye mi) maro (Si le mi) Maro (Sona mi o) Ase Oluwa ni
Ojo ibukun maaro saye mi
Ase Oluwa ni
Koseni to le da duro tori asiko mi tito
Ibukun agbongbe sori iran mi
Ojo ibukun to daaju
(Maro maro) maro maro
(Maro sori mi) maro sori mi
(Ojo ibukun Maaro maro ooo Ase Oluwa ni) Maro Maro Ase Oluwa ni
Jesu pase ojo sori iyangbe ile mi
Lati mu eweko tutu jade
O pase itura sibi ta ti n ni mi lara lominira bade
Iwosan to peye f'ago ara mi
Ise Oluwa leyi ooo
Ore ofe nla ni mori gba
Ore ofe to daaju
Maaro ojo maaro ase Oluwa ni
Ojo itunu ojo itura ma to ase oluwa ni
Maro o maro o sori mi, maro maro Ase Oluwa ni
(Ro lemi Lori o)
Ojo ibukun mo toro
(Ojo ibukun ma da lewa lori o)
Ojo ibukun la nfe
(Ma a ro, Ma a ro) Maro sori mi (Hee) maro (Heee) Maro Maro o ase Oluwa ni
(Ojo ibukun lat'odo Oluwa o)
Ase Oluwa ni
(Ojo itura, ojo itunu,ojo ipese)
Ase Oluwa ni
(Ko maro lori aye wa lori ise wa yeeye)
Maro (Hee) Maro (Maro) o ase Oluwa ni
(Ase Oluwa ni)