Ajanrete Lyrics
- Genre:Folk
- Year of Release:2022
Lyrics
Ajanrete - Bayo Ododo
...
Olu n rete
Olu n rete
Ile pelu olorun
Won ba p'eku emo kan
Ile l'ohun l'agba
Oloun l'ohun l'egbon
Ile b'amu eku emo lo
Oloun ba b'inu lo s'orun
Ojo b'ako ni o r'omo
Isu p'eyin k'ota
Agbado t'ape k'ogbo
O'lomoge gun mu omu gbe
Esa mo f'oye s'orin
Emo f'oye s'orin
Orin ti d'orin olowe
Awa yoo f'oye si o.
Awon kan k'ora won Jo
Won l'awon l'agba ilu
Awon kan k'ora won Jo
Won l'awon l'agba Oye
Awon kan k'ora won Jo
Won l'a won fe tun ilu wa se
Won ba l'ogbon Apapin
Won tun l'ogbon ewe
Won ba f'ari apakan
Won tun s'ara rindin
Won o ranti awa mo
Esa mo f'oye s'orin
Orin ti d'orin o'lowe ye
Awa yoo f'oye si o
Won r'elu oba
Won f'iwa y'otomi
Won n'jegudu jera
Won wuwa isotito
Esa mo wo won l'oye
Ibikan l'oma j'asi ye
Awa yo w'owon l'oye o
We plead for the change2×
For the change o
Ani ka won kan mo je igbadun
Ka won kan mo r'elu oba
Ka won kan mo j'iya
Iyen oda o
We plead for the change o2×
For the change
Ani ka won kan mo w'oso
Ka won kan mo wo a'kisa
I'yen o da ooo