Nigeria Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
Nigeria - Temi Praise
...
Nigeria !!!
Iwo ilu, ti ada
Tonsan fun waara
Ati fun oyin
Kilo wa de
Tomoonile wa fi daaleje
Awa npara nitori, ija esin
Aparawa nitori eyameya
Aparawa, bi eni peefan
Iwe mimo sowipe
Nibo logun ti wa oo?
Nibo lotee si tinbo?
Seebi laarin wa ni
Nigeria 2x
E o si furaa
chorus - Ibaawi oluwa leyi oo, afi kàgbadura (2x)
kooluwa kowa yo.
Lead- Isu han koose je
Gaari han kose ra
ohun gbogbo jije oo
loti gbowo lori oo
afi kaagbadura
kooluwa kowa yo
choru- Ibaawi oluwa leyi oo, afi kàgbadu(2x)
Ko somo soyo mo ooo
Soti jeun loku oooo
Omo kaawe tan, won korise se
Nigeria eje kàfura
chorus-Ibaawi oluwa leyi oo, afi kà gbadura, koluwa ko wa yo
Ogun nile, ogun looko
Ko sifokan baale mo oo
Ohun gbogbo loti yi pada
Nigeria eje kaafura
cho- Ibaawi oluwa leyi oo, afi kà gbadura, koluwa kowa yo.
Onile oni lesun
Alejo onile wo
Ife oluwa, kosi mo oo
ife owo oo, loku tanba kiiri
ch- Ibaawi oluwa leyi oo(2x), afi kàgbadu koluwa kowa yo
Awon tanwo bi jigi oo
Won se ibaaje oo
Woli njaale, oyani leenu
Agbere, iro piipa
o keere
ch- Ibaawi oluwa leyi oo, afi kàgbadura, koluwa ko wa yo
Lead- Afi kaagbadura eh eh eh
ch- Afi kàgbadu koluwa ko wa yo
Afi kàgbadura, solorun, awon olorun
ch- Afi kàgbadu koluwa ko wa yo
Led- Afi kàgbadura soluwa awon oluwa
ch- Afi kàgbadu koluwa ko wa yo
Lead-Adura lolese, eje kàgbadura
ch- Afi kàgbadu koluwa ko wa yo