IJEBU Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2022
Lyrics
IJEBU - Jesse King Buga
...
telling me telling me by the way
emi ọmọ ìjèbú
Ijebu ọmọ alárè
ha Aye wo lao jẹ rí
tell them tell them let them know say
won Le won o Le ba
them dey see us them dey emulate
they won begin dey imitate
may be someday them go graduate
many many people no know how far
baba as e dey go
owo lomo gbagbe osi
Ijebu awujale
Ijebu ọmọ alárè
kekere ijebu o kekere Ijebu o owo
awọn to mowa o àwọn to mowa o won jelo
àgbà Ijebu o àgbà Ijebu o owo
awọn alabosi o àwọn alabosi o won a jegba
ariya rẹpẹtẹ Ijebu ọmọ wa o gbeske
mo jelo ati jelo
Ijebu jo jo jó jo jo dada
Ijebu jayé Oba ha ha jayé oba
we don dey ball we dey represent
olowo lomo Seyi ohùn
Ijebu lomo koso si
Aye wo lao jẹ rí
tell them tell them let them know say
won Le won o Le ba
Ijebu awujale
Ijebu ọmọ alárè
kekere ijebu o kekere Ijebu o owo
awọn to mowa o àwọn to mowa o won jelo
àgbà Ijebu o àgbà Ijebu o owo
awọn alabosi o àwọn alabosi o won a jegba
opo po po opo opo po po
opo po po ọmọde wẹ yin nu
mofo ko yin nu
opo po po
ha oro wen le we lẹjọ ninu
lèyìn kín ma jayé òrúwo mi
fàájì we ne colour riwe wá
ọmọ yemi sì ko go on soun
kekere ijebu o kekere Ijebu o owo
awọn to mowa o àwọn to mowa o won jelo
àgbà Ijebu o àgbà Ijebu o owo
awọn alabosi o àwọn alabosi o won a jegba