
Omo Adamo ft. Sola Shittu
- Genre:World Music/Folklore
- Year of Release:2016
Lyrics
Omo Adamo ft. Sola Shittu - LC Beatz
...
Mo ni label pẹlu management Mo ni lawyer ti o ni consent Awọn sponsor won ki n dakẹ jẹ Awọn fans mi n fun mi n respect Omo This is the reality I gat every popularity I Sabi I Sabi them authority Omo mo ti wa fẹ di principality Gbọ mí So lọ f′eniyan sasọ bora ni Tori p'on fún ẹ Bugatti Ti ki ní kan ba lọ ṣẹlẹ ọmọ wọn má salọ wa a fi wọn s′awati O le niyan oloun ni something T'oba l'ọlọrun wọn má ni nothing The best defence is my God the blessing Èmi kò gbara lé ọmọ Adamo ti won kole se rara Emi kò gbara lé ọmọ Adamo ti won le ba mi Laye jẹ Emi ko gbara lé ọmọ Adamo ti won ko le se rara Emi ko gbara lé ọmọ Adamo ti won le bami kaye jẹ Mo ni daddy mo ni Mummy Mo ni grandpa mo dẹ ní grandma Mo ni uncle mo ni aunty Mo l′ẹru ku mo dẹ ni cousin In fact mo mọ Gomina It′s a matter of pé kín pé wọn So mòye fans and followers to mo ni to jẹ nkan to ba kan mi ti kan wọn Otutu fete O da pe ọ ti fẹ tẹ Mummy tan e wò mi tan candle Ìyẹn ni itanra eni jẹ Mo le ni Yan mo dẹni something Tan ba l'ọlọrun wọn má ni nothing Igbekele eniyan asan lo já sí Mẹ male gbara láwọn Emi ko gbara lé ọmọ Adamo Ti won kole se rara Emi ko gbara lé ọmọ Adamo Ti wonle bami laye jẹ Emi ko gbara lé ọmọ Adamo Ti won ko lese rara Emi ko gbara lé ọmọ Adamo Ti won le ba mi Laye je Listen I can never never gbara lé wọn o Torí ìyẹn o dáa ìyẹn o wapaa rara See I′m warning you Ma lọ gbara lé wọn Ehh Baba óò Má gbara lé wọn ṣe Ko ma lọ tẹ wo mi ran Ma gbara le wọn ṣe Ko ma lọ tẹ wo mi ran Igbẹkẹle asan ní Gbọ mí dáadáa Ma gbara le wọn ṣe ko ma lọ tẹ ẹlòmíràn Listen attentively Ma gbara le wọn ṣe ko malo tẹ womi ran Ehn eheh. Shola shittu o Ehn hn hn Lcbeatz.
Similar Songs
More from LC Beatz
Listen to LC Beatz Omo Adamo ft. Sola Shittu MP3 song. Omo Adamo ft. Sola Shittu song from album G.A.G.A (GOD and GOD Alone) is released in 2016. The duration of song is 00:03:33. The song is sung by LC Beatz.
Related Tags: Omo Adamo ft. Sola Shittu, Omo Adamo ft. Sola Shittu song, Omo Adamo ft. Sola Shittu MP3 song, Omo Adamo ft. Sola Shittu MP3, download Omo Adamo ft. Sola Shittu song, Omo Adamo ft. Sola Shittu song, G.A.G.A (GOD and GOD Alone) Omo Adamo ft. Sola Shittu song, Omo Adamo ft. Sola Shittu song by LC Beatz, Omo Adamo ft. Sola Shittu song download, download Omo Adamo ft. Sola Shittu MP3 song