Ese Baba
- Genre:Gospel
- Year of Release:2005
Lyrics
Baba baba baba oya a baba oya a baba oya a baba oya a baba oya baba
Aye sebo ti tan awon ore won tun yi eyin pada
Mo ba gboun mi soke so oluwa olorun alagbara lo bashiri mi
Ibanuje pari eru ose ti tan mo yin o baba omo emi mimo
Iwo nikan lore otito o soro mi dayo ope ye o baba
Ese o oo ese baba ninu aye mi o ese baba
Baba o gbemi leke daddy ese baba lori satani o ese baba
A ope ye o baba mow a dupe o o fun mi layo
Ogun aye mi oti wo patapata o iwo koje kaye bere olorun mi da
Ija ti dopin ogun ota ti wo apata ayeraye o ni jagunmolu mi
see lyrics >>Similar Songs
More from OJB Jezreel
Listen to OJB Jezreel Ese Baba MP3 song. Ese Baba song from album Jah's My Lite is released in 2005. The duration of song is 00:08:15. The song is sung by OJB Jezreel.
Related Tags: Ese Baba, Ese Baba song, Ese Baba MP3 song, Ese Baba MP3, download Ese Baba song, Ese Baba song, Jah's My Lite Ese Baba song, Ese Baba song by OJB Jezreel, Ese Baba song download, download Ese Baba MP3 song