- Genre:Juju
- Year of Release:1980
Lyrics
Sanu Olu - Chief Commander Ebenezer Obey
...
Sanúolú omo oloye mase gbàrá le eniyan, nitorí aye ma soro. Sanuolu omo oloye mase gbàrá le eniyan, nitori aye má soro. Aiye Aiye gboká. Aiye Aiye soro o. Sanúolú omo oloye mase gbàrá leniyan, nitorí aiye má soro. Soyóyo. Igbekele eniyan Àsan ni o, Asan. Igbekele eniyan asan ni o. Sanúolú boro kan ba yo, toba jòró àrá re. Iwo kanu so maba eniyan só rárá. Nitori onibaje làyé won feni fóró o. Nigbati omin jegùn, ení kan ori e. Owa di igba ilabe, inu wa nbi won o. Pakúte mose nise on mekú o. Sanúolú o mo ise nise, orowolo o . Pakúte mose nise on mekú o, sanúolú o mo nise orowòló Sanúolú baba ewe o Sanúolú baba ewe o
Similar Songs
More from Chief Commander Ebenezer Obey
Listen to Chief Commander Ebenezer Obey Sanu Olu MP3 song. Sanu Olu song from album Olomi Gbo Temi is released in 1980. The duration of song is 00:02:53. The song is sung by Chief Commander Ebenezer Obey.
Related Tags: Sanu Olu, Sanu Olu song, Sanu Olu MP3 song, Sanu Olu MP3, download Sanu Olu song, Sanu Olu song, Olomi Gbo Temi Sanu Olu song, Sanu Olu song by Chief Commander Ebenezer Obey, Sanu Olu song download, download Sanu Olu MP3 song
Comments (2)
New Comments(2)
Adeleke Turnup
Hacapela
yy
[0x1f611][0x1f611][0x1f614][0x1f631][0x1f632]Good