- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2012
Lyrics
Jesu Ni Balogun Oko - Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
...
Jesu ni balogun oko, e mase je ka foooya, olu toko wa ni Jesu, e mase je ka foooya, e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Gba ti gbi aye yi ba n jaaa, lo rokun ati nile, akoko nbe ti o daju, lodo Olugbala wa, e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Metalokan alagbara, da bobo awa omoore, lowo ategun ati 'ji, je ka wa ka le lu yah. e mase beru, e ku fun ayo, nitori Jesu loga oko, bo ti wu ki 'ji na le to, yoo mu oko wa gunle.
Dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si. dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si. Dawa si, dawa si, dawa si, dawa si, ise po ta wa yo se, nitorina da wa si.
Similar Songs
More from Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District)
Listen to Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District) Jesu Ni Balogun Oko MP3 song. Jesu Ni Balogun Oko song from album Ibi Ikoko Oga Ogo (His Secret Place) is released in 2012. The duration of song is 00:04:37. The song is sung by Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District).
Related Tags: Jesu Ni Balogun Oko, Jesu Ni Balogun Oko song, Jesu Ni Balogun Oko MP3 song, Jesu Ni Balogun Oko MP3, download Jesu Ni Balogun Oko song, Jesu Ni Balogun Oko song, Ibi Ikoko Oga Ogo (His Secret Place) Jesu Ni Balogun Oko song, Jesu Ni Balogun Oko song by Cherubim & Seraphim Movement Church (Surulere District), Jesu Ni Balogun Oko song download, download Jesu Ni Balogun Oko MP3 song
Comments (6)
New Comments(6)
Emmytee007jeakd
Yemisi Peter
I Love This Song
Jhayskwin
Cherubim and Serapim is going to high places in Jesus Name
Olalekanga0zsga0zsga0zs
lovely
Akin Awosejo
nice song
103827379
nice song
im blessed by this song...more grace in Jesus name