
ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live)
- Genre:Spirituals
- Year of Release:2024
This song is not currently available in your region.
Lyrics
ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) - Sola Allyson
...
ṢỌLÁ'S CLASSICS 2
Fatusin Alexander O.O added lyrics:
Femi bi oju tin fe mu, femi bi irun tin fori, femi bi ehin tin fenu, femi temi temi, femi tokan tokan, femi tara tara, ololufe feranmi laisetan o.
Chorus: Ife bi eji owuro, la ta gbala Eledumare lo ti se wa, Ife ee to toro mini mini, tabawon aye kan ole baje ooo, ololufe feranmi laisetan oo
Ama lowo lowo, ama bi mo lemo, ama sayo mayo, ama sola mola, ka sa mu fe Eledumare se laisetan oo(2x)
Ife bi eji owuro, la ta gbala Eledumare lo ti se wa, Ife ee to toro mini mini, tabawon aye kan ole baje ooo, ololufe feranmi laisetan oo
Orekelewa omoge abe je tutu, abife loju atokan t'omo lolo oninure olokan re, to ko lenikan ninu afi kose jeje, oniware, oninure, bo ti yan tire, oyato si temi, bi mo ti yan temi, oyato si tire
Similar Songs
More from Sola Allyson
Listen to Sola Allyson ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) MP3 song. ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song from album 20 Years After EJI ÒWÚRỌ̀ Concert (Live) is released in 2024. The duration of song is 00:02:31. The song is sung by Sola Allyson.
Related Tags: ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live), ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song, ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) MP3 song, ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) MP3, download ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song, ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song, 20 Years After EJI ÒWÚRỌ̀ Concert (Live) ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song, ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song by Sola Allyson, ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) song download, download ṢỌLÁ'S CLASSICS 2 (Live) MP3 song