![Lowo Olorun Lowa](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7_WAU4vsAACLK5YoYqQ859.jpg)
Lowo Olorun Lowa
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Lowo Olorun Lowa - Tope Alabi
...
Ara emama jeka gbagbe pe aye lajo orun nile wa. Ope ni, oya ni, iku ni lati muwa lo, erin loni ekun lola aye lajo orun nile wa. Atipo ni aje laye, alejo ni aje o he, ojokan ni baba yio pewa pe omo ma bo kowa sile o. Ojokan na ni baba yio pewa pe omo maa bo kowa sile o he. Gbogbo ara koni wulo fun alara mo, beni olorun to faramo amo koni wulo fun olorun, emi wa nikan lonlo jiyin ise tose, nile itura didan ta oti fida wa lele ti a o fade wa lele. A o pawa larada, ao de wa lade ogo, ao sigbe wa niyawo nile ogo lodo baba. Emama je kagbagbe o pe ajo laye yi orun nile wa, boni kaluluku tin naja loja o, been akoko nlo ile nsu o, bile bati su dandan nika rele wa o ajo laye o orun nile wa. Emi lore meji sibadan komi ko leta o, ikan lo won jedun won wedun doja titi mi o redun ra o tori eeyan ledun. Ikan lo won josupa, owo mi oto, ile ologo o ilu ayo mimo o, ile ologo ilu ayo mimo o, olorun saanu fun mi jekin le ba ojoba, Jesu saanu fun mi o, Jesu saanu fun mi o jekin le ba o joba. Jesu yii wasaye lati wa ku fun ese wa, a ki bimo nile ewure ko yaso aguntan loje. Ijo ojokan bo tifa o peran topolo o peran tiyawo o lota ti yo sebe kode ni je nibe sin ni yo ma dun.Faye e fun jesu oluwa. Toripe be korogbo, be kobi kena sibi yin kogun, be korogbo be kobi kena sibi yin kogun, efori bale lati esin de idunta ewo hmm ohun tesu agba niyo gba,toba ku die kesun a gbekun wa. Afuni lookan fi gbeede gba ni satani, toba ku die keniyan sun ohun gbogbo tesu nika fokan bale le lori a wa ma bere, a ma beere lowo eni. Awon kan tita emi won fesu, awon kan tita emi omo won fesu, won rope ohun tesu o gba loti gba yen, won o mope aye tesu o gba ni ogba, orun tesu ogba ni ogba, toba ku di e kesun agbekun wa. Afun e laye agborun lowo e, tori na faye e fun jesu kojo tope.
Similar Songs
More from Tope Alabi
Listen to Tope Alabi Lowo Olorun Lowa MP3 song. Lowo Olorun Lowa song from album Live Concert - Praise The Almighty Concert is released in 2014. The duration of song is 00:19:48. The song is sung by Tope Alabi.
Related Tags: Lowo Olorun Lowa, Lowo Olorun Lowa song, Lowo Olorun Lowa MP3 song, Lowo Olorun Lowa MP3, download Lowo Olorun Lowa song, Lowo Olorun Lowa song, Live Concert - Praise The Almighty Concert Lowo Olorun Lowa song, Lowo Olorun Lowa song by Tope Alabi, Lowo Olorun Lowa song download, download Lowo Olorun Lowa MP3 song
Comments (108)
New Comments(108)
Ashade Adenike
tebez
❤️
Jacques falanan
seigneur
![Image | Boomplay Music](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/19/d6289f7cfc41492589198aac5622495b.jpg)
Samuel Yisawoo9e
alway feel very,and inspiring happy whenever,i listening to your songs ma,more strength
Oluwafemihem09
Amen ooo Thanks Jesus
Samuel Haroley
Aunty mi owo julo. Spiritual Mother. You are Gods' sent
ADETAYO98
[0x1f623]
David Iyanda
may God continue to empower you ma
KYLE JOY
i love this, so meditating
Yinkuzzi
deep
chasermilli
she always given joy
Margaret Popoola
More grace
More anointing