
Adura Mi (My Prayer)
- Genre:Gospel
- Year of Release:2023
This song is not currently available in your region.
Try the alternative versions below.
Alternative versions:
Lyrics
Ma ma je p tan ogo ni nu ofoo I wo isenda Mi ee owo ko wo ogbodo Teri aye mi ba ori Mi jowo ma gba abode Ile olora Mi ko gbó don di a sale fi ti la Mi to mó le rekete oluwa ten imole si okunkun aye mi má ma je kabamo pe ki ni mo waye fun igi mi tò ruwe ko ma se wowe lojiji Ina ogo mi ko ma gbodo ku lojiji gbogbo owò to wa lenu ise fun ibi gbogbo ese toun wa Lori Orin fun ibi gbogbo enu to wa Lori aroka to wa Lori ibaje lati ja mi bòn ayeraye koluwon ooo oluwa koluwon bo se ko lu ogun faraoo ko lu won Kan ma se gberi món gbogbo Eni to ba fi mi ré la o fi ré gbogbo eni to ba fi mi bu la o fi bu gbogbo eni ba yonu si Mi ni ki o yonu si gbogbo fun ba binu Mi ni ko korira gbadura ooo gbadura fun awon toun gbadura fun Mi gbogbo eni ba pon mi le ni ki o ba Mi pon le ma se je ki ogun aye ko bó ri mi oo ma se gba gbe lati pa eni toun fe pamirun amin ooo Asa ti ko wi pe gbogbo ti mo ba se ni yoo ma se denu den atiko wi pe ibukun ni funmi ni ile mi ibukun ni fun mi ni gbogbo Ona mi ibukun ni fun Mi lajo ibukun ni fun awon omo inu Mi ATI eso Ile mi ibukun ni fun mi nigba ti mo ba wole ibukun ni fun mi nigba ti mo ba jade asiti ko wipe oluwa yoo pase ibukun si ori gbogbo ti ma ba fi owo Mi le leyin gbogbo eyi to oluwa olorun ti pa lase si nu ayemi ti a ba wa ri eni ke ni ti a bi ninu obinrin abi ti a fi Abe gba ebi ee toun fe da oju Mi bole laye toun se ise lodi si ATI gun oke mi laye adaniwaye ooo
null
null
Similar Songs
Listen to Mojisinuola Adura Mi (My Prayer) MP3 song. Adura Mi (My Prayer) song from album Adura Mi (My Prayer) is released in 2023. The duration of song is 00:05:14. The song is sung by Mojisinuola.
Related Tags: Adura Mi (My Prayer), Adura Mi (My Prayer) song, Adura Mi (My Prayer) MP3 song, Adura Mi (My Prayer) MP3, download Adura Mi (My Prayer) song, Adura Mi (My Prayer) song, Adura Mi (My Prayer) Adura Mi (My Prayer) song, Adura Mi (My Prayer) song by Mojisinuola, Adura Mi (My Prayer) song download, download Adura Mi (My Prayer) MP3 song
Comments (38)
New Comments(38)
Lawal Morenikejia9wh5
gentle soul 931
so lovely to listen
☬Ⱥđɇøłⱥ☬
[0x1f623][0x1f623][0x1f623]
Odunayo Eniola1k3a0
i love this song
Alimi Ajibade
sister please keep it up [0x1f623][0x1f623][0x1f623]
FatieBam
This is a very beautiful piece. More grace and anointing ❤️
Temiladesl057
I love this song God is great
GRATIAJEE
really adura mi....Amin Jesu
Timilehin n8g85
kudos, emotional song
gentle soul 931
ádùrá fún àwọn tó gbàdúrà fún mi
gentle soul 931
❤️❤️❤️❤️
Bill Bulk
[0x1f623][0x1f623]
[0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623][0x1f623]