![Isale Eko (Live)](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/3E/27/rBEeMVlTlO-AfY1XAABj5HY5P74342.jpg)
Isale Eko (Live) Lyrics
- Genre:Fuji
- Year of Release:2015
Lyrics
Isale Eko (Live) - K1 De Ultimate
...
Ìsàlẹ̀ èkó o
Ibẹ̀ ṣá l'orísun
Adámu òrìṣà
Ọkọ́làbà
Ọlọ́gẹ̀dẹ̀
Ẹ̀yọ̀ onígo
Ẹ̀yọ̀ àǹgéré
Ìsàlẹ̀ èkó
Àwa ló niwọ́n
Tiwa ni wọ́n mí ṣe
Bẹ gbẹ́'ran wá
Ibẹ̀ ná ń dádé