![KARI](https://source.boomplaymusic.com/group2/M0C/C7/10/rBEeNF2xjV2AOF9oAACs3BV9Ads493.jpg)
KARI Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2019
Lyrics
Kari
Written and Composed by Sola Allyson
Produced by Mr Wols
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Mo m'ope wa Baba wa gb'ope
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Alaanu u mi mo m'ope wa
Repeat
Alaanu u mi o - mo m'ope wa
Nigbati eniyan ko mi le Iwo l'O gbe mi ro
Olutoju mi Olugbamila Olugbamile Oluwa
Enit'O s'aanu mi o
Alaanu u mi o
Nigbati ogun le Iwo l'O so pe alaafia
Alaafia fun emi mi alaafia fun okan mi
Titi aye ope mi ree lat'ogbun okan mi nigbagbogbo
Alaanu u mi o
Mo ri idariji mo ri aanu
Mo ri itona mo ri iso ati abo nigbagbogbo
Alaanu mi o
Modupe Jehovah modupe
Mo dupe Jehovah modupe
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Jehovah l'O ba mi se
Eledumare l'O ba mi se
Atofarati l'O ba mi se
O ti tan 'mole s'ona mi mi o ni si'na o
Oun l'O gba mi, o gba mi o so mi d'afomo
O tun tan imole s'ona mi mi o ni si'na o
Modupe Jehovah modupe
Mo dupe Jehovah modupe
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Fun imole t'Óo tan s'aye mi O se o
Iwo t'O tan imole, Olutanmole t'O tan'mole s'ona mi Oluwa o
Maa fi imole yi tan'mole, maa fi gbe ogo Re ga Oluwa
Imole t'o tan sinu okunkun, okunkun mi fo lo, imole mi ò ni ku lailai, okunkun mi fo lo
Olutanmole t'O tan'mole, aye mi tire ni igba mi tire ni.
Ona t'O pe mi si mo nto
Ise t'O ran mi ni mo nse
Ipe t'O pe mi ni mo je
Aye esu ese k'o mase de mi l'ona
Ki n s'aseye aseyege niwaju Re
Repeat
Modupe Jehovah modupe, etc
Oba t'Ó ni ebun mi
Oba t'Ó ni emi i mi Oba t'Ó l'emi gangan
Imole t'o ntan nibiti imole ti ntan, ko lee ku lailai, ko lee ku lailai o
Imole mi ntan, imole mi a maa tan atupa mi a maa jo geere ko le ku lailai
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye o!
Iranwo yoo maa wa
IMUSE yoo maa de
Agbara yoo maa so
Ohun mi a kari aye o!
Ni iro ohun mi gbogbo ese a sare wa
Ni iro ohun mi gbogbo okan a sipaya lati ni irapada si igbala Re
Ni iro ohun mi eti a te beleje, lati gbo ohun Re iyen nikan l'o ye n gbigbo
Ni iro ohun mi oju á la sile kedere
Lati ri O, Eni naa t'o ye n riri
Ohun mi a kari aye!
Ohun mi a kari aye
Ohun mi a kari aye o!
Iranwo yoo maa wa
IMUSE yoo maa de
Agbara yoo maa so
Ohun mi a kari aye o!
--- www.LRCgenerator.com ---