![Nii 94](https://source.boomplaymusic.com/group2/M0C/A2/F9/rBEeNF2RQEGAamveAADThbBZAsk058.jpg)
Nii 94 Lyrics
- Genre:Holiday
- Year of Release:2016
Lyrics
Nii 94 🅴 - Dargin
...
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4,
(4) ,Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Mo ranti igba ti Buki shi wa ni primary 4, Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4
Ni kekere, o wun pelu Yewande
Awon omo kekere yen ma ti dagba gan ni isin yin
O ranti igba ti ama n ko won lo si jelosi mi
Awon na ti'n jo SeanPaul ninu club
Shebi mummy won lowa ni ibi kan ti won tin se rub, ni ibi odo aboki kan to man sun si inu shop?
Hehe
Awon omo yi ma ti di omoge o
Mo pe Bukky la no
O so fun mi wipe shege
Ak
O ranti awon omo yi tehtey
Omo fi oro sile na today? E don tey
Awon omo ti won man fi iyepe se ere panti
Ki won to ji laaro wo ma ti to si ori eni
Awon mummy wan ma ni wipe kin gbe wan lo si odo nani
Sugbon won ti dagba ni isin yi
Wo o fe mo mi
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen
Bukky ti di omoge mo wa lowa
O ranti e mi brother Korede ni kekere?
O ranti gbogbo igba ti e si ma un fi yepe sere
Loojo Sunday Sunday ti ma fun gbo yin ni feere
Dakun maa lo momi mo
Maa fi agba sere
Oti e ni ore e kan ti won man pe ni Titi
Titi si ranti igba ti mo man fun yin ni sisi
Mori Titi lano gbogbo orimi mi titi
Mo ni Olorun gbami, gbogbo yin leti di sisi
Ni '92 ni gba ti esi wan ni Primary 2
Won ni efe se party ni school, o ni o ma ra kon shoe
Nitori ti e, mummy e ran lo si Kotonou
Mo wa n so oro ni isinyin, oso fun mi kin meshonu
Iwo to je wipe o man fi iyepe se ere panti
Ko to ji laaro wo ma ti to si ori eni
Awon Mummy wan ma ni wipe kin gbe wan lo si odo nani
Shugbon o ti dagba ni isin yi o o fe mo mi
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4
Gbo iyen itan ma niyen
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen, (yen)
Bukky ti di omoge mo wa lowa
Amo igba ti Buki shi wa ni primary 4, (4) Nii 94
Nigba to shi ma n wo pina 4, (4)
Gbo iyen itan ma niyen