
Olarenwaju (Live) Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2019
Lyrics
Ọlanrewaju (Live)
Written and Performed by Olawale Ọlọ́fọọ̀rọ̀ Brymo
Produced by MikkyMe Joses
Live performed by The Lagos Touts
Instrumental
*Crowd cheer*
The next song is titled Olanrewaju
Why you think se I wear native come
Igba o lo bi orere
Bo ba koro osi maa dun ah
Eni to ni suuru kii s’eyan kekere
Bo ba kan le, osi maa kan’ke ah
Boo ba se un to fe, won maa keyin si e (ehn a ehn)
Bo ba se tire o, o ma je’re fun e
Olanrewaju omo Oba,
E ma suure da gba o
Won ni ko o se were, roora se
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku si bi ?t? ooo
Olanrewaju omo mi,
E ma suure da gba oo
Igba o lo bi orere
B’omode oku oo, osi maa da gba
So’ra funja, So’ra f’egbekegbe
Oun tio to o, osi maa po da nu
Gbogbo eni abi lo ma ku
Iwa ta a wu lo ma ku
Olanrewaju omo Oba,
E ma suure da gba o
Won ni ko o se were, roora se
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku si bi ote ooo
Olanrewaju omo mi,
E ma suure da gba oo
Olooto ko ni ku sibi ote oo
Olooto ko ni ku sibi ote oo
Olanrewaju omo Oba, ee ma suure dagba oo
Olanrewaju omo mi, ee ma suure da gba oo
--- www.LRCgenerator.com ---