BABA JE KI OGO MI SORO Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2022
Lyrics
BABA JE KI OGO MI SORO - Bose Adekunle
...
baba je ko ogo mi soro
tori ogo to soro laye gbo o
baba je ko ogo mi soro
tori ogo to soro lo gbadun aye
baba je ki ogo temi na soro
tori ogo to soro late gbo o
baba o je ko ogo mi soro
tori ogo to soro lo gbadun aye
Akoko egbe dide ti to
olorun awon baba wa
bo ogo oba soro
omo eleran asi ma je egun
bo ogo ba soro
omo alaso asi ma wo akisa
bo ogo na soro
omo oba a oma sese eru
bo ogo ba ko ti o soro ogo yo odi niyen
bo ogo ba ko ti o soro ogo ya aro niyen
bo ogo ba ko ti o soro ayamo asi ma sun asun pin ye
abi ewo in ogo to soro nigbati ologo ti da gbe re fun aye
(back to chorus)
bo ogo ba ma soro
mo ni lo onigbo wo la