
Ibukun Olohun 1 Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Ibukun Olohun 1 - ALH. KABIR ALAYANDE ERE ASALATU
...
Yah salam
Ki se temi, ki se temi,ki se temi
Oriburuku ki se temi
Ah ah
Yah rabbi yasir wallah tuasir, yah rabbi yasir wallah tuasir
Wajali umurah sallah yasirah, wajali umurah sallah yasirah
Olorun
Kun kun kun kunfayakun
Kun kun kun kunfayakun
Gbogbo n ti Mo beere olorun fa se si o
Da kun ma je n jeka pe kini Mo waye fun x2
Yah rabbi
Olorun mi aseda mi, olorun mi aseda mi
Emi mo ni isadura iwo lo ni gbigbadura
Remilekun olorun mi ko pin si kotokoto aye mi x2