![E Ki Remix](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/09/27/adb40332f0614b579e03961d55b0c841.jpg)
E Ki Remix Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2021
Lyrics
E Ki Remix - Bola Discovery
...
ah ah eba mi ki jesu
gbogbo eniyan to ba mo riri
ise lo se lse lo see
Lori aye wa Lori omo
Lori oko
eba mi ki
chrs:eki eki oh ×2
eba mi ki jesu po ku ise
eba mi ki jesu po ku ise
verse: ise lo see jesu lori aye mi
oku fun emi otun was jiya to
ye kin je
asa o logbe Ade o lade egun
nitori emi ni
mo wa ki o jesu olugbala
ku ise iyanu
(btc interlude)
verse:mo ni o ni baba oh
ni mo se n Yan
emi ni o leyin mi ni mo se
n sako
opomulero aye mi
igi leyin ogba mi
emi ki o jesu oku ise mi
iwo lo segun fun mi
baba lai mumi lo
o n duro timi o je
ko ju o ti mi rara
iwo lalanu mi olutunu okan mi
emi ki o jesu olugbala ku ise iyanu
(btc interlude)
verse:mo mo riri
mo mo riri
mo mo riri re
olowo gbogboro
to yo omo re ninu ofin
iwo labiyamo to ponmi
gege to o je n jabo
mo rowo re laye mi o
ise lo see
ise lol se lowo lowo lowo
jesu lori aye mi
ilorin ti o dun ti o togbe
Tori kemi le sun Ni
kabiesi to da iku sugbon to o ni ku lai
emi ki o olorun ti o juwe ise lose
(btc interlude)
verse:mo ki o jesu Moki o oh
mo ki o jesu mo ki o
emi ki o jesu pe ise lo
n se lowo lowo
eyi to n se lojojumo jesu laye mi
mo ki o
(btc mo ki mo ki oh)
call:eba mi ki o
all: e ki
call:ni gbogbo iseju
all: e ki
call: olorun ni gbogbo ojo
all: e ki
call: kabi esi Ni gbogbo igba
all: e ki
eba mi ki jesu po ku ise