Wa (Come) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2019
Lyrics
Wa (Come) - Debanke
...
First Stanza:
Emi Mimo wa,
Wa, wa ninu agbara re.
Mu Ibukun wa,
Wa, wa ninu agbara re.
Afe ri o o, Emi Olorun,
Jare wa, wa ninu agbara re.
Afe ri o o, Emi Olorun,
Jare wa, wa wa ninu agbara.
Refrain:
Eeeeeeeeeeeeeeee a
Eeeeeeeeeeeeee
Eeeeeeeee
Second Stanza:
Emi Mimo wa,
Wa, wa ninu agbara re
Mu ibukun wa,
Wa, wa ninu agbara re.
Afe ri o o Emi Olorun,
Jowo wa, wa ninu agbara re.
Afe ri o o, Emi Olorun
Jare wa, wa ninu agbara re.
Biko ba si Iwo Baba, kole si awa
Jare wa, wa, wa ninu agbara re.
Biko ba si Iwo, Baba mi o kole si awa.
Jare wa, wa, wa ninu agbara re.
Call: Mimi wa o,
Response: wa o
Call: Wa o
Response wao
Olubukun wa o
Biko ba si Iwo, kole si awa
Holy Spirit get down
Let your Presence fill this place
Holy Spirit come down
Let your anointing fill this place
Oh Abba Father, Come down
Let your glory fill this place,
As we gather here,
Wa ninu agbara re.