Ikilo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2000
Lyrics
[ti:03 Ikilo]
Ibosi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi ojo
Amo mo ri o (x2)
Iku o je a dagbere fun eni keji eni
Biku ba pa alade oko a da
Eyin ka ile ** wo
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Ibosi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Iku a pa babalawo bi eni tio mo ifa
Iku a p’onisegun bi eni tio mo ise
Iku p’ojise olorun bi eni tio mo oro olorun
Iku to pa abile wunmi oshofa
Lo pa ajanlekoko lo tun pa abiodun bada yi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi ojo
Amo mo ri o
Ibosi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Ibase pe ani ku laye
Kashiri baba baba baba mi o
Ibase pe ani ku laye yi
Kashiri mamamamama mi
Amo gbogbo wa la dagbada iku
Emo seni tio ni rorun o
Orun dede ma mo kanju mo gbogbo wa la nbo o
Orun dede ma mo kanju mo gbogbo wa la nbo
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Ibosi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Abiodun bada baba erin
Igba to togba tin shigba nle **
Konko to to konko tin se baale odo
****
Amo ni shey ayi ma ranti re
Baba rere baba wa ke eledumare o de ile fun o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Ibosi o
Amo ri baba mo
Amo ri mama mo
Baba mati kun lo bi oyin o
Amo mo ri o
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o (x2)
Se oti ku no nu ni
E o ni se oti ku no nu ni
E o nise oti rele no nu ni abiodun
Ah o ma se o ile ma nje eyan
O ma se iku ma me ni
Iku ma mu eni ire lo
O ma se iku ma doro o
Abe iku be iku iku o gbo ebe o
Iku mo doro o
Amu owo to owo iku loun o gb’owo
A mu obi to to obi iku loun o gb’obi
A ko aso to to aso iku loun o gba aso
A mu edende gberun owo iku loun o gb’owo
Se oti lo no nu ni
Se bada ti lo no nu ni
Ki eledumare je ko **
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o
Mon wa eko lojo owuro ojo yen
Bi kowe se ke maleika ni mo rope nke
Kowe yi ke lo o ke bo
Be kowe e ke lasan
Ese erin ti wo
Kowe kowe nke lasan rara
Ara o bale ara se ojo
Be no ni mo nronu pe isele nla wo lo sele
Mo ranti olododo segbe
Enikan o ka si ***
Sugbon orun olododo losi waju lo
Siwaju ibi lorun
Oma se o
O ma se o
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o
Gbogbo ijo mimo patapata
Eku ilede baba rere to lo o
Abiodun ti se iwon to le se baba ti lo
Alexendar ti se iwon to le se baba ti lo
Ise wa ki sowo gbogbo wa o
Ka ma mo je o baje o ara mi
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o
Ma sun olufe
Sun le aya olugbala re
Afe o sugbon jesu fe o ju
Sun re
Sun re
Sun re
Lola alagbase tan o
Oun gbogbo ti pari
Lola alagbase tan o
Ise iya ti pari
Lola alagbase tan o
Kirakita aye pari
Lola alagbase tan o
Ogun ejo ti tan
Lola alagbase tan o
Tembeleku pari
Lola alagbase tan o
Oro eri ti bere
Lola alagbase tan o
Ogun ti tan iya dopin
Kama dupe lowo eledumare ni
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o
A o pade leti odo
Lese angeli ti te
O mo dara bi crystal
Leba ono odo olugbala
A o pade leti odo
Odo didan odo didan no o
Pelu awon mimo leba odo
Ti nsan leba ite no
Ese aye re
Ema se aye re
Abiodun ti se o jagun molu
Ese aye re
Ema se aye re
Lokunrin lobinrin eje a saye ire
Eni nko ese re
Ese aye ire o
Ese ko dara
Ese ko ma dara
Ese ko dara
Ese ko ma dara
Eyin nko ese re
Ese ko da
Abiodun ti se tie oti lo
Oti gbade iye gbade ogo lodo baba
Wahala abiodun o ja sa asan
O se gudugudu meje ati yaya mefa
Ese aye re
Emo saye re o
Eni aye mo ese re o
Ese aye re o
Ara ma wo mi niran
Ara ma wo mi niran
Imo bami daro baba lo
Abiodun o ma ni pada mo
O mo se o
Iku fowo we owo
Won jo kole afara oyin
Eru fi imoran we imoran
Ajo sha nile o
Ka sowopo ka fife lo
Ka fife lo ka sowo po o
Ka ma ma yara wa ati otun ati osi
Ka fara wa mora
Iyapa o gbodo si mo
Abiodun ti rele oti ko gbogbo ija wa
Ka fi ife han ka sowo po
Osusu owo o ma shoro se
Agbajo owo
E agbajo owo ni
Agbajo owo la fin so aya no ara mi
Ijo mimo
Ijo emi mimo olorun
Nibi toba mimo ngbe shola
Nibi toba mimo ngbe shogo ni
Kafi ife lo ka sowo po
Ki keferi ma ba gbere wa lo
Ka fi ife lo ka sowo po
Kalayi mokan ma gbere wa lo mo wi to o e