
Gbemisoke Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2016
Lyrics
Baba wa gbemisoke
Iwo ni mo gbe okan mi le
Nigbati aye ba komi sile
Baba yio duro timi
Oun lore otito
Dakun mase fi mi sile
Lai lai
Baba wa gbemisoke
Iwo ni mo gbe okan mi le
Nigbati aye ba komi sile
Baba yio duro timi
Oun lore otito
Dakun mase fi mi sile
Lai lai
Gbemisoke baba
Iwo ni mo gboju le
Ninu aye yi
Ninu aye yi
Wa sola mi di pupo
Sola mi di pupo
Wa tunmininu baba
Tunmininu
Nigba gbogbo
Nigba gbogbo
Ninu aye yi
Ninu aye yi
So mi dolola o
So mi dolola
Baba wa gbemiskoke
Wa sekun mi derin
Nigbati ishoro ba gbemi sanle
Baba yio duro timi
Oun ni ore otito
Dakun mase fimi sile
Lai lai
Gbemisoke
Gbemisoke baba
Iwo ni mo gboju le
Ninu aye yi
Ninu aye yi
Wa sola mi di pupo
Sola mi di pupo
Wa tunmininu baba
Nigba gbogbo
Ninu aye yi
So mi dolola
Wa gbemisoke baba
Olola ni mi
Olola ni mi
Ola ayi lopin
Ola ayi lopin
Ni mo yan
Ninu jesu mo di asegun
Olola ni mi
Ninu jesu moti di asegun
Olola ni mi
Ola ayi lopin
Ibanuje kosi fun mi mo
Ni mo yan
Olola ni mi