Tribute To Late Chief Obafemi Awolowo Lyrics
- Genre:Juju
- Year of Release:1987
Lyrics
Ah omase ile yi jeniyan 2x
Iku pa obafemi awolowo 2x
Ah omase ile yi jeniyan 2x
Ah omase ile yi jeniyan 2x
Iku pa obafemi awolowo 2x
Ah omase ile yi jeniyan 2x
Awo awolowo 2x
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Baba sasotele koto ku
Awolowo sasotele koto lo
Baba sasotele koto ku
Awolowo sasotele koto lo
Igba tawo mak oko sile lo 2x
Oun ni e ma sukun oun
Eferan ara yin
E firayin sekan
Oun ni e ma sukun oun
Eferan ara yin
E firayin sekan
Awo awolowo 2x
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Kosin ekun kosi ofo
Lowo awolowo
Kosin ekun kosi ofo
Lowo awolowo
Awo awo awolowo 2x
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Korimi mo lawolowo
Niki ofo foun
Korimi mo lawolowo
Niki ofo foun
Awo awo awolowo 2x
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Eja nla lo lomi ewiwo 2x
Obafemi awolowo lo
Onlo ile aiye lo
Onlo ko duro denikan
Onlo ile aiye nlo
Onlo ko duro denikan
Onlo ile aiye nlo
Onlo ko duro denikan
Iroyin iyanu lo jasi fun wa
Ema sunkun ema sofo
Baba ni kema sofo
Baa mi awolowo
Awolowo rele
Baa mi awolowo
Awolowo rele
Awolowo boluwa ke
Oti sefe
Awa omo africa
Iroyin iyanu
Lole jasi fun wa
Emasunkun ema sofo
Baba ni kema sukun
Baba awolowo be laye
O duro lori otito
Igba tawolowo be laye
O duro lori otito
Won ku leyin e wonku loju u e
Sibe sibe oduro lori otito
Won ku leyin e wonku loju u e
Sibe sibe oduro lori otito
Ibi e reti e doju ko
E di eyi to je otito mu
Ibi e reti e doju ko
E di eyi to je otito mu
Kama weyin kama sojo onibi otito
Iku awolowo seri bo seri
A oni gbagbe re titi
Obafemi awolowo
Ile iwe ofe
A oni gbagbe re titi
Obafemi awolowo
Ile iwe ofe
Free education
Ile iwe ofe
Free education
Eto ilera ofe
Free health services
Eto ilera ofe
Free health services
First television service ni africa
Awolowo ose o
A o ni gbagbe re titi 2x
Obafemi awolowo
Ile iwe ofe
Free education
Ile iwe ofe
Free education
Eto ilera ofe
Free health services
Eto ilera ofe
Free health services
First television service ni africa
Awolowo ose o
Osemilanu omase o ikuseka
Oko yeye oba omase ikuseka
Oko didun olurele omase ikuseka
Baba omotolarele omase ikuseka
Oko didun olurele omase ikuseka
Baba oluwolerele omase ikuseka
Babayo baba tokunbo
Baba segun osemilanu o omase ikuseka
Baba o awoloworele
Oko hannah oko dideolu
Sunre o baba
Baba o awoloworele2x
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere
Awolowo iba eni osoreni koiku 4x
Ilu reni nigeria ye ma foje o 2x
Ye ma foje o 4x
Egoje lori awolowo ibamolola
Egoje lori awolowo iba oluwole
Egoje lori awolowo iba ayodele
Egoje lori awolowo iba tokunbo
Egoje lori awolowo iba olusegun
Atunse fun iwe
Oko chief hana oko dideolu
Aiye o aiye ewa weyin oku awolowo
Agbagba pelu ewe
Aiye o aiye ewa weyin oku awolowo
Agbagba pelu ewe
Ojo toro osu dede 2x
Awolowo tibesan je aiye ibare
Aiye igese erora
Awolowo orun o
Orun le je ji wa saiye
Ei sowo omo eniyan
Orun lesa tiwa saiye
Jeremiah obafemi awolowo
Omo egun yela lele
Jeremiah obafemi awolowo
Omo egun yela lele
Jeremiah obafemi obafemi awolowo
Omo egun yela lele
Jeremiah obafemi obafemi awolowo
Omo egun yela lele
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere
Kato rerin odigbo
Kato refo odandan
Kato reye kiyo kiyo
Awolowo iyen digbere