![Radical Praise Side 2 (Bonus)](https://source.boomplaymusic.com/group2/M01/1C/B7/rBEeM1tzLQ-AJALnAADt6Kx4UoM672.jpg)
Radical Praise Side 2 (Bonus) Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
Radical Praise Side 2 (Bonus) - Lanre Teriba (Atorise)
...
Koro bi mose n se
Koro bi mose n wuwa
Eee
Olorun Koro bi mose n soro
O sa n toju MI lojojumo
Eee
Koro bi MO ti n se
Kode to bi ti n wuwa
Koro bi MO ti n soro
O sa n toju MI loojojumo
Intrumentalist
So n toju MI lojojumo?
Ohun tojumi loojoojumo
Drums
Sohun tojumi lojojumo?
Koro bi MO ti n se,
Koro bi mose n soro
O Sa n toju MI lojojumo
Intrumentalist
KI ise mimoo se
Ki ise agbara mi
Kide ise titobi mi
Lofi damisi o o babaoo