![Radical Praise Ni](https://source.boomplaymusic.com/group2/M01/1C/B7/rBEeM1tzLS6AUT2dAADW0hLTbAM790.jpg)
Radical Praise Ni Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2018
Lyrics
Radical Praise Ni - Lanre Teriba (Atorise)
...
Oluwa Etobi , Etobi o etobi,
ko se ni ra ke fi shakawe re o. Eto bi/2x
oluwa
olorun , Olorun , oruko re ti popular to lagbaye, tori re la se n yin o
kini mafi San ore re baba
kini mafi San ore re omo
Ope lope re/2x
aye iba yeye mi
opelope re.