Oluwa O Seun Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2006
Lyrics
Oluwa O Seun - Lanre Teriba (Atorise)
...
……..
Osan
Jeko san mi sowo
Ale o
Ale yiii
Ko na mi la
Osan
Jekosan mi sowo
Ale oooo
Aleyiii
Konamila
Boje lowuro
Tabi lasale
Bojesale ni
Tabi lowuro
Baba gbe remiko mi
Olorun gbe ayo mi bo wa funmi
Moji lowuro yii o je kin ba re pade
Beats….
Ibikibi Timolewa
Olorun mi shanu aye mi
Ayekaye timo lewa
Eleda mi shanu aye mi