![Iranlowo (Help)](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/00/18/rBEeM1fu7qGAXCqfAACUa59sBCk545.jpg)
Iranlowo (Help) Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Iranlowo (Help) - Lanre Teriba (Atorise)
...
Olorun o!
Nibo loju re wa more ri o (×2)
Dide togun togun
Dide tija tija
Dide ninu agbara re e
Dide nine agbara re e
Kiwo si gbo adura mi
Ojo ti npa'gun bo ojo ti pe
Awon aye ti nwo mi b'eni ti o le dahun rere se
So da be kan foruko re yomi
Olorun
Nje o fe bee kan foruko re gun mi ni
Mo de mo pe oo sunlo, ipe Apostle Babalola o
Mo de mo pe oo sunlo, Olorun Orimolade
Omo oya ti un poya, Omo oloke meji tako-tabo
Oni nla t'olorun gbe kale silu Ikare nibo lo wa mo fe ri o
Moni mo mo po s sunlo, Olorun Bilewu Oshofa
Nibo loju re wa mo fe ri o
Eyin malaika ti un se rere, ti kii seka nibo loju re wa mo fe ri o
Ase ti un sise lori Oke Olorun Kole
Are ti un sise lori Oke Ikoyi nibo lo wa mo fe pohun rere se Nile aiye
Ase ti un sise l'Erimo mo fe ri o
Ase ti un sise l'Agelu
Olorun Olowere nibo loju re wa more ri o
Tori mo mọ p'osunlo Olorun Obadare o
Mo de mo po o sunlo, Olorun Baba Abiye l'Ede
Nibo loju re wa mofe ri o
Emi mo po sunlo Olorun Hezekiah l'Erinwo
Olorun Gabriel Adome, Olorun Baba Keji ni Mushin
Olorun Altimate Malaika abiyamo aboja gboro-gboro
Nibo le wa mofe ri o
Dide e dide (×2)
Dide ninu agbara re, Olorun Olukoya
Olorun Eunuch Adeboye, Olorun Baba Agbona mofe ri o
Olorun Ajayi Ogidiolu, onikanga ajipon
Olorun Oyedepo,
Olorun Biodun Adebowale
Olorun Fapohunda mofe ri o
Olorun Joshua Temitope,
Olorun Kasali o,
Oba to ran afoju nise, to r'ohun toloju meji o ri laye,
Bami to s'ogbo d'ile, Olorun mi to, s'ogbe d'igboro,
Not by power, dide ninu agbara re,
Dide t'ogun t'ogun, dide t'ija t'ija,
Dide ninu agbara,
Dide ninu agbara o,
kiwo si gbo aadura mi.
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan
Olorun oju re mo nwo mama pada lehin mi,
Ire mi to un be ni gusu tabi l'ariwa
Eyi to un be n'ila oorun, tabi n'iwo re e
gbawon fun mi Baba, nibi t'aye fisi
Ojo nlo lasiko yi s'aanu mi
Toba lo pe just, aiye a se yeye mi
Dide iwọ ori mi
Ojo nlo lasiko yi s'aanu mi.
Boti wu k'orun naa muto
Sanma dudu die yo wa
Boti wu k'aiye wa l'ayo o
Yo lakoko ẹkun re
Gbadura
Gbadura wa Oba olore
Gegebi awa ti un ke pe wo
Make je k'awa omo re rahun
Latunbotan aiye wa.
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan
Aiye un bu mi, eniyan un bu mi
Oti wa un re okan mi
Aiye un l'emi, eniyan un l'emi
Oti wa un re okan mi Baba
Ranti mi l'oni o, ojo nlo
F'owo tu mi sile Jesu, f'owo agbara tu mi sile (×2)
Ibi aiye d'emi mo, Olorun tu mi sile
f'owo agbara tu mi sile
Oluwa
Mo gbo pe iwo ro ojo 'tunu kiri,
Itunu fun okan wa re
Ro ojo naa sori mi
Aa l'emi, Aa l'emi
Ro ojo naa s'ori mi
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan
Olorun ranti mi loni o, oojo nlo
Aginju aiye l'emi wa,Baba a ranti mi
Moti sare sare l'aginju o ti wa un re okan mi
Ranti mi loni o oojo nlo
S'egan mi d'ogo o Jesu, wa yori mi s'oke (×2)
Oba to'pe samo kowa yori mi s'oke l'aiye
S'egan mi d'ogo o.
Aanu re Oluwa la un toro,
Ro ojo rẹ le wa
Eye ti un fo, a t'era t'orile
Ni won lopo-lopo.
Aanu re
Aanu re Baba, Aanu re Omo,
Aanu re Baba wa orun l'awa un toro,
Eye ti un fo, a t'era t'orile
Ni won lopo-lopo.
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan.
Oluwa, akoko to o, j'ewo agbara re
Jesu, akoko to o, j'ewo agbara re
Oluwa, akoko to o, j'ewo agabara re
Jesu, akoko to o, j'ewo agabra re
'Toripe
Mo un woju, Olorun mi
Emi un woju re e, Eleda mi
B'omokunrin ti un wo owo Baba re
B'omobinrin ti un wo owo Nama e
Emi un wo Jesu titi yo fi dami l'ola.
Baba a,
Ni iwakati yi
Gbe'se owo re ga a
Ki gbogbo aiye le mo, p'ẹyin le un ranmi nise,
la'san, l'aiye un gbe ogun
Wakati naa de ta mi wariri l'abe agbara mimo, Jesu.
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan.
Aanu re la un toro Baba
Olubukun aiyeraiye
Ire to bukun fun-un eyin bo
Jowo wa bukun wa
Aanu re la un toro Baba
Olubukun aiyeraiye
Ire to bukun fun-un eyin bo
Jowo wa bukun wa
Iranlowo alalenikan, iranlowo alailenikan (×2)
Nibo loju e wa, nibo loju re wa a fe ri o
Oju aanu re da, s'okale wa
Ojo nlo lori mi oti wa un re okan mi
Iranlowo alailenikan.
Emi mimo no mofe,
Olorun alagbara,
Ara k'ole sise emi, Olugbala gbemi wo.
Emi mimo no mofe,
Olorun alagbara,
Ara k'ole sise emi, Olugbala gbemi wo
Jeri ara re o Baba, jeri ara re (×2)
B'ose jeri ara re niyara oke l'ojosi
Jeri ara re
Mo mọ p'osunlo, Emi awon wooli
Nibo l'oju re wa mofe ri o
Olorun Gbenga Olusoga nibo lo wa mofe ri o
Mo de mọ p'osunlo Olorun Onowa mimo
Nibo loju re wa mofe ri o
Dide t'ogun t'ogun
Dide t'ija