
Stop It ft. Segun Nabi Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2024
Lyrics
Ju’life king x Segun Nabi
Yeah… it’s Segun Nabi and Ju’life King all the way from America
Ye ro nu mo, ore o
Ironu o da nkan aisan lo ma gbe wa
tu’ju ka ma ba’nu je o si ma daa (o si ma daa) b’ekun pe daale o ayo mbo lowuro
Ayo Ayo Ayo mbo o
Ye ro nu mo ore o (oremi) Ironu o da nkan aisan lo ma gbewa (calm down) tu’ju ka ma ba’nu je (calm down) o si ma daa, bi ekun pe daale o ayo mbo lowuro
Ki lo se e ti o s’enikan ri
Ori bi be ko ni ogun ori fifo
A bi ki lo se e ti se enikan ri
Ori bi be ko ni ogun ori fifo
The down fall of a man is not the end of the world
Shoga mo so temi, ti ibi ti ire ni ile aiye
Ire de ni ko je ti wa, ko je tiwa, ko je tiwa
Ye ro nu mo ore o
Ironu o da nkan aisan lo ma gbe wa
tu’ju ka ma ba’nu je o si ma daa (o si ma daa) b’ekun pe daale o ayo mbo lowuro
Hmm, Akanbi Segun Nabi mo ki ilo iwa ni temi, iwa lo’ba awure wa ti ma gbo
Shoga lo ni ki n da si mo daa si
Oremi ba wo ni ‘wa re lawujo
Iwa re la ma gbeni san’le, la si ma la’na fun ni, lamori subu nitori o ku na iwa ni ironu ba de, it’s never too late to make adjustment
Imoran mi re Olusoga Adigun o
Ore mi wo bi ti o ti bere, se o fi otito si
Wo bi ti o ba de, se o se ‘mele, abosi, ote, ika tenbeleku, gbogbo e pata lo ma backfire
What goes around comes around, ro’nu jinle se atunse, ola mbo wa dara o eeh
Ola mbo wa dara o dandan
Ma fi ironu se ra re le se, se atunse
Ola mbo wa dara o dandan
Ola ma better Ola ma sure o
Ola mbo wa dara o dandan
Ta le ni to so fun o o pe ko si atunse mo
Ola mbo wa dara o dandan
Ko si ohun to soro se sa ti ni ‘gbagbo ninu Oluwa
Ola mbo wa dara o dandan
Emi Olusoga ni mo so fun e personal experience mi ni
Ola mbo wa dara o dandan
Pa ‘ronu ti tu ‘ju ka ni ‘gbagbo ninu Oluwa
Ola mbo wa dara o dandan
Iwa rere le so eniyan, te ‘pa mo ‘se pelu adura o yeah
Ola mbo wa dara o dandan
Ironu o daa nkan olorun o fe iku elese
Ola mbo wa dara o dandan