![Oruko Oluwa](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/00/21/rBEeMlfvCUSAeXy1AADAhOWm3-E846.jpg)
Oruko Oluwa Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2012
Lyrics
Ma yin o olorun to dara ton soungbogbo fun mi o
Emi o yin o imole ton fon awon mi o e
Ore re koja siso o kan mo e e
Ona re ma gbe mi o arinye ni o
Ona re ma gbe mi o arinye ni o e e e
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Awon torun fogo fun elemi eda
Olowo re lati orun de aiye o orin lori omo okun
Oruko re nikan lo ko aiye ja agbara nikan ni ko lepin
Ko seni to le gbogo re pin lailai
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Gbogbo aiye wa riri labe re eda gbogbo lo gba o loga
Oun to da lorun ati aiye ko le ri di agbara re o e e
Won o le ri di agbara re o aseda mi
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Alade ogo iba re o olorun to dara iwa re wun mi o
Mo wa o mi o ri oba to ba bi re ninu gbogbo oba
Oluwa oluwa oruko re niyi
Oluwa oluwa oruko re niyi
Nigbogbo aiye o oruko re niyi
Ninu awon orun o oruko re niyi
Apepe tan oloruko pupo titi lailai oruko re ko le pin
Titi aiye oruko ko le pin
Oluwa oluwa oruko re niyi
Oluwa oluwa oruko re niyi
Nigbogbo aiye o oruko re niyi
Ninu awon orun o oruko re niyi
Apepe tan oloruko pupo titi lailai oruko re ko le pin
Titi aiye oruko re ko le pin
Alagbara olododo atobiju loluwa
Alayiro loluwa oruko re un gbani la
Oruko re gbemiro oruko so ni doloro
Oloruko a pe ni re
Oluwa oluwa oruko re niyi
Oluwa oluwa oruko re niyi
Nigbogbo aiye o oruko re niyi
Ninu awon orun o oruko re niyi
Apepe tan oloruko pupo titi lailai oruko re ko le pin
Titi aiye oruko re ko le pin
Oruko re un ja funi
Oruko re un gbe iku mi
Oruko un fona han mi
Oruko taiye se
Ibi gbo ruko re o pare
Okunkun gbo wole lo
At the mention of your name every knee must bow
Oluwa oluwa oruko re niyi
Oluwa oluwa oruko re niyi
Nigbogbo aiye o oruko re niyi
Ninu awon orun o oruko re niyi
Apepe tan oloruko pupo titi lailai oruko re ko le pin
Titi aiye oruko ko le pin
Oruko ti ko le baje ni mo beri fun
Oruko ti o le pin san sir
Oruko oluwa o ile iso
Oruko oluwa ni pa agbara ni
Oruko oruko oruko oruko oruko nlanla
Emi ni ona owe tito iye Ilekun kokoro imole ododo
Jesus Kristi messiah okuta odi gbo odo aguntan rere
Apata aiyeraye apata aiyeraye apata aiyeraye apata aiyeraye
Apata aiyeraye apata aiyeraye ni