Ebi Opa Mi Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Ebi Opa Mi - Ojoblizz
...
Ebi o pami débi tin ma sope olorun osi
Òùngbẹ o gbe mí débi tin ma kán lẹ kun ota mi
Asiri mi otu loju aseni bani daro
Bàbá òkú iṣẹ lórí ìgbésí ayé mi
mo regbe mi ton sale lakitan
mo tí regbe mi tí wọn dá wọpọ fún jẹun lorita
mo tí regbe mi ta yé tí ya ní were oOoOO
Emi ọsẹ ni yin ọ o baba

Ebi O pami débi tin ma sope olorun osi