![Se Bo' Timo](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/05/2B/rBEeNFf9BuSAaG2rAACr9zMFjbA806.jpg)
Se Bo' Timo Lyrics
- Genre:Afropop
- Year of Release:2013
Lyrics
Ijapa o n'ibi ti o n lo
Kele kele, o n rin, o n lo
Ara ile n yimu, o n lo
Ero wa, ero lo, o n lo
Ko gba agidi
O ro bi A, B, D
Ti o ba koju mo tie
Ti mo koju mo temi
Baba fi eyin si owo otun,
Ki a feyin sowo osi,
K'awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin
Eni ma yini, a yini
Eni o ni yini, Ko ni yini
Se bo'timo ore
Se bo'timo ore mi
Se bo'timo mama
Se bo'timo baba mi
Won n tan e
Dakun ye maa tan ara re
T'ire n T'ire
Ye ma ko ara re
Bi o ba sare, bo subu
Iwo lo lara re
Bi o le, bi o ro
Ore, ma paara ire
Ko gba agidi
O ro bi A, B, D
Ti o ba koju mo tie
Ti mo koju mo temi
Baba fi eyin si owo otun,
Ki a feyin sowo osi,
K'awa f'eyin rin lati ahin titi de iseyin
Eni ma yini, a yini
Eni o ni yini, Ko ni yini
Se bo'timo ore
Se bo'timo ore mi
Se bo'timo mama
Se bo'timo baba mi
{Instrumentals till fade}