![JUBILEE 2025. OFFICIAL HYMN YORUBA LANGUAGE. ARINRINAJO IRETI (PELLEGRINI DI SPERANZA / PILGRIMS OF HOPE)](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/02/23/19920d4c70c7415bb8b3618c16a55505_464_464.jpg)
JUBILEE 2025. OFFICIAL HYMN YORUBA LANGUAGE. ARINRINAJO IRETI (PELLEGRINI DI SPERANZA / PILGRIMS OF HOPE) Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
Ègbè:
Iwo iná ireti mi tó n jó
Je ki orin mi goke wa sodo re
Iwo ayeraye Orisun iye ti ko lopin,
Mo gbekele o ninu irinajo aye mi.
(1)
Je kí gbogbo awon eniyan at'orílẹ̀-èdè
Rí ìmọ́lẹ̀ nínú Oro rẹ.
Kí àwọn aláìlera, lokunrin lobinrin ti won ti fonka
Rí ibùgbé nínú Ọmọ rẹ ọ̀wọ́n
(2)
Ọlọ́run ìkẹ́ àti sùúrù, maa se itoju wa
ni ibere ojo iwaju tuntun yii,
Ki Emi Iye Re ko gba aye koja
ki o si so Orun at'Aye d'otun
(3)
Gbé ojú sókè, ba afefe Iye to n fé rìn
Yi pada: Olorun n bo
Wo Omo Olorun to gbe àwò eniyan wo
Ki egbe-legbe ba a le e ri ona iye.