Intro ft. Ewwunmi D Enchantress Lyrics
- Genre:Others
- Year of Release:2024
Lyrics
Imole yoooo
Won Shebi Osu loyoo
Imole yoooo
Won Shebi Osu loyooooo
Olorire ti yoo
Alaye ire ti yooo
Imole nbo lona ooo
Imole nbo lona
Gbogbo okunkun e parada ooo
Be mewun Erin
E san gbiwun Erin
Be omosa yen ji yolobe
Imole olorin lo yoo
Akola re fomo olorin