![Agbelebu](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx7uKAG6rpAAB29xXIOkE234.jpg)
Agbelebu Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Awa eda to l’orun da (awa eda)
Aiye oto ototo lawa (aiye oto)
Oni kaluku lo yan ayamo (beeni)
Aiye agbelebu lawa
O o o o o o hun o o o eh eh
Agbelebu oooo
Ede to wa si ile aiye
Ka to le lo a o sukun o (a o sukun o)
Aiye agbelebu lawa
Ta ba bi omo tuntun jojolo o
Tibi tomo ni yo kowo ru bo w’aiye
A kehinde omo aladarin omo
Ibi sha loruko re je
Ibi ati ri ibi eda ole so
Igba ibi defun eda omo l’aiye
Eyi wa se ari daju wope
Eda to w’aiye pelu ogun na
Aseda to da wa
O o o oo o o o o eh eh
Agbelebu ooo agbelebu o ni gun merin
Eda to wa si ile aiye
Ka to le lo a o sukun o
Aiye agbelbu lawa
Ba ti wa aiye pelu ibi
Be l’aiye pelu ayamo
Apoti ogo o ba wa w’aiye
Kokoro to si on’be ninu adanwo
Bi a ba sin ibi a kin sin ogo
Ogo farasin si aiye eda gbogbo
Ka to le lo a o segun na
Kokoro ogun ayirin a gbodo wa (a o ti se wa)
Awa eda to l’orun da (a de fi kawa o)
Aiye oto ototo lawa (ka to le si apoti o)
Oni kaluku lo yan ayamo (oni kaluku lo yan ayanmo)
Aiye agbelebu lawa
O o o o o o huh huho o
Agbelebu oooo
Ede to wa si ile aiye
Ka to le lo a o sukun o (a o sukun o)
Aiye agbelebu lawa
Sa ba bi ni agbelebu je
A ma ja si re fun awon to ba le gbe
Elejo wewe kin lle gbe agbelebu
Won ma b’ogun aiye won ro jo
Tasiko ba koja lo won o ni fura
Jobu koju ida wo l’aiye
Kaka ko fi ejo se olorun
O gbe agbelebu re layi wo eyin
Igba ti isoro tan e wa wo ara
Ara nla ti olorun fi da
O o o oo o o o oooo
Agbelebu oooo
Ede to wasi ile aiye
Ka to le lo a o sukun o
Aiye agbelebu lawaa
Ala yi nibe re so agbelebu deru
Won so ogun igba die di oba won
Won wa foribale fun
Isoro basi joba laiye eda to
Ole se be peni ron se dojo ogbo
Iru wo kin le ro ire mo ra won
Ko da won tun so de bi olorun
Won ma gongo ori imu adani waiye
Ti won fi owo jun
Ika a kun inu won wo o ni le bon i re yo
Ise woyin lo mu won gbaiye
Be eniti ko gbo ogo wo aiye yi rara
oooooo
Awa eda to l’orun da
Aiye oto ototo lawa
Oni kaluku lo yan ayamo
Aiye agbelebu lawa
O o o o o o ooo
Agbelebu oooo
Ede to wa si ile aiye
Ka to le lo a o sukun o
Aiye agbelebu lawa
Ayi le gbadura
Ayi gboran pupuru ese ati ikan ju okan
Omu ki ota lo asiko agbelebu
Lati gba emi lenu elomiran
Awon omo isreali so irin ajo ogoji ogo
Dogoji odun mo ra won lowo
Serin afowo fa ati ayi ni suru
Ati ayi ka abgelebu kun ebo gbigbe
Ko je ki elomiran ko mo ona ati rin
De bi ogo ogo re
Eriri aiye kole tin i pa e jowo
Inshe ni o fogbon ko eda l’aiye
Se wa ri agidi ogbon agbo ju eniyan
A mu kelomiran ma wo apoti ogo won lokankan
Layi ni le debe
Olorun fi ileileri won mose
Sugbon ko de be rara
Olorun kin da majemu to ba enikeni da
Beeni labe akoso boti wun kori o
Olorun je o lododo
Ko ni se dalebi lonakanno
Oooooooo oooooooooo
Abgelebu ooooo
Eda to wa sile aiye
Ko to le yo a sukun
Aiye agbelebu lawa
Eyan to yo se lokan kole kun
Won kan ju won gbe se ni meji meji
Won fe fo lona abgelebu ti won
Se l’aiye won gbojikan fun isira satani
Amo ona to wo ebo
Aiyisan a pa ni ku saiye
Paya yi layi wo okan
Iku ayi to jo wa lo bi rere
Ola ti ipanju da won niyen
Layi mo pe ko si adanwo ti enikan o ri
Awon to ka si won o ni iriri
Eniti ko ni e iriri ko le ni eri
Ma je ki agbelebusoe di alayi gbagbo
Nishe lo ye ko fun o lagabra
Nitori o fi asiri ikoko wonni
Ati ba o se to laiye ba o se fe to laiye
Ani bi a o se to laiye ba o se re lo to laiye
Oro gbogbo odowo re aseda (o dowo re aseda)
Ayi fi ka be olorun ko gbo
Agbelebu dandan agbelejika
Ka mo leru ka ya tete gbe
Oro gbogbo o dowo re aseda
Ayi fi ka be olorun ko gbo
Agbelebu dandan agbelejika
Ka mo leru ka ya tete gbe
Eniti ol e sa ko so okan re
Ko ni le gbe agbelebu de ibi ogo
Ko to de ni afokan tan a o ye o wo
Irubo loje o ko nipe tan
Olugbala nagbe to eri o
Ko to gba ade ogo ojuboro ko
Ona agbelebu ja si koto jasi bebele
Bo tin huh be o ko ma gbadura
Ma si ye meji ko ma ba se lasan
Ma jowu ogo o logo layida
Ko ma ba jiya lo silkeun ti fo
Gbe gbe tele olugbala
Oruke jesu lowo ile ogun
Oruko jesu ile iso agabara
Olododo sawo be o si ri iye
Gbe agbelebu re o e bo re ni
Fi igbagbo gbe o gba gbogbo e si ayo
O fere debe na o da mi loju
Ki lo mo to je agbalebu re
Oun ko oun lo le je beere mole ko ya gbe (yara beere gbe)
Agbelebu atete gbe atete debe
Adani waiye fi adawo so ibi dire beeni beeni
A ma gbe tie tegan tomije koyi biomo o
Omo isreali gbe ti won pelu ekun kan ile ileri
Ruth gbe agbelebu pelu ikoro ara e gbo o
O kuku gbe tan o leri to po to ga o
Iran ruthu lati bi jesu oluwa wa o
Bori ba ti mo lo se un o fo olori
Ologo nla irubo kenken
Eleda n wo omo adamu ko te le fun
To ba fun e saju o le ma mo lo oo
Owo ban wi ile lo tan fun ni
Abraham je ore olorun oju lasan ko
Josefu o fi oju boro de po oja lamba
Igbele nibi jabesi ko to se re re
Ki estheri to di aya oba oti sin ilu ri o
Ma reti eniti o rn o ti o ban gbe lowo
Abgelebu da da gbe a jo so
Juju l’aiye wa ki olorun to pe imole
Ona agbelebu aji ju eru ni
To ba mu ramu ramu ma ba wo yin o
Ko si eniti o nigbe afi alayi ni ogo
Gbe pelu igboya wato de be
A mu ni pade pade pade
A mu ni pade angeli a banise
Awa eda to l’orun da
Aiye oto ototo lawa
Oni kaluku lo yan ayamo
Aiye agbelebu lawa
O o o o o o o o
Agbelebu oooo
Ede to wasi ile aiye
Ka to le lo a o sukun o
Aiye agbelebu lawa
Lagbara baba o (lagbara baba o)
Lagbara baba orun (loruko jesu)
Awa yio de bi ogo lokan (lokankan)
Ipin wa ko ni fo wa o (etewo adura)
Kokoro ogo a ri gba
Apoti ogo ma de be si
Emi ni yio je ere ogo mi
Orun o ni wo mi o ma gbe dele
Eniti to lo ema wo eyin
Eniti o simi e tese mo rin ema yi ti simi
Eniti ti o ja jun segun oun lo simi
Aiye de la raiye de lo ri re
Lagabara baba oo lagabara baba orun
Lagabara baba o lagbara baba orun
Ogun rere sa ni ipin mi
Emi ni yio je dogbo
Lagbara baba o lagbara baba orun
Ogun rere san i ipin mi
Emi ni yio jere