![Edumare Ma Seun O](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/29/rBEeMVfx8RGAAlrFAAB7629JiXo243.jpg)
Edumare Ma Seun O Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2010
Lyrics
[ti:05 Edumare Ma Seun O]
Mo duro mo rire o
Edumare ma seun
Mo bere mo rire
Edumare ma seun
Ire owo wole mi o
Ire omo lo tele
Ayiku wole mi moti fi jesu se apata abo mi
Ire ni mo yan o (x2)
Oluwa ni imole mi ati igbala mi
Tani emi yio beru ko ma si o
Oluwa ni agbara emi mi
Aya tani o fomi no o e
Mo duro mo rire o
Edumare ma seun
Mo bere mo rire
Edumare ma seun
Ire owo wole mi o
Ire omo lo tele
Ayiku wole mi moti fi jesu se apata abo mi
Ire ni mo yan o
Moyin olorun Abraham
Baba to bu iwa si orun
Eni aye ayinepekun eni olorun nfe
Jehovah oba nla o
T’aye t’orun njewo re
Mo wole mo ko mimo o
Temi o ma yin lailai lai
Mo duro mo rire o
Edumare ma seun
Mo bere mo rire
Edumare ma seun
Ire owo wole mi o
Ire omo lo tele
Ayiku wole mi moti fi jesu se apata abo mi
Ire ni mo yan o
Kini wun o fun olorun mi
Fun gbogbo anu re
Won o fa ebun ni
Won osi ma fi irele bere si (x2)
Kini mati se ti nko sin lorun
Kini mati se ti nko sin baba
Kini mati se ti wun oni sin lorun
Kini mati se ti wun oni sin baba
Mo se ebo shebo
Ebo o le gbemi o
Mo se ogun shogun kole gbami la
Mo tun rele alawo ofo lo jasi o
Kini mati se
Kini mati se
Kini mati se o ti wun oni sin baba (x2)
Mo duro mo rire o
Edumare ma seun
Mo bere mo rire
Edumare ma seun
Ire owo wole mi o
Ire omo lo tele
Ayiku wole mi moti fi jesu se apata abo mi
Ire ni mo yan o
Afayi la ojo
B’ojo ba yo loni o ma la o
B’ojo ba yo loni o ma la o
Ire ni mo yan o
Ire ni ipin mi
Ire ni mo yan o
Jesu labo mi o
Oja imo ikun ki won ma ma bu
Emorija jeki temi asi ire lodo re o
Olubukun ode orun
Afayi la ojo
B’ojo ba yo loni o ma la o
B’ojo ba yo loni o ma la o
Ire ni mo yan o
Ire ni ipin mi
Ire ni mo yan o
Jesu labo mi o
Afoju lowo o eleru niyin o
Ma shayi gbowo ya nile mi
Owo owo owo
Owo iworo
Owo ni keke iyin re re o
Afayi la ojo
B’ojo ba yo loni o ma la o
B’ojo ba yo loni o ma la o
Ire ni mo yan o
Ire ni ipin mi
Ire ni mo yan o
Jesu labo mi o
Ba ba buni leyin omo eni a ja a fara ya o
Kin ma ma rerun omo o
Komo mi yan ki won yanju o e
Afayi la ojo
B’ojo ba yo loni o ma la o
B’ojo ba yo loni o ma la o
Ire ni mo yan o
Ire ni ipin mi
Ire ni mo yan o
Jesu labo mi o
Ba ba lowo kunle
Ba ba leshin lekan
Alafia lori oun gbogbo
Alayisan o gbadun bi abarapa
Abarapa ti gbogbo aye loka re le kan ni
Gege bi iri ti nse si ori eweko gbogbo
Jeki emi mimo re o olorun
Ko ma se sori wa
Kama rayo ninu ise wa
Kama rayo ninu ile wa
Kono wa ma la si rere
Afayi la ojo
B’ojo ba yo loni o ma la o
B’ojo ba yo loni o ma la o
Ire ni mo yan o
Ire ni ipin mi
Ire ni mo yan o
Jesu labo mi o
Atoba jaye o adimula oba
Arugbo ojo o agbalagba baba
Akikitan ose o agbalagba la nla
Onile ologo alalede anu gboro mi ro
Oba adani ma gbagbe eni
Atoba jaye o adimula oba
Ijinle ife olorun anu
Arugbo ojo o agbalagba baba
Akikitan ose o agbalagba la nla
Oba gbori ite sh’ogo
Onile ologo alalede anu gboro mi ro
Oba kiki imole kiki ogo
To tan imole didan nla
Atoba jaye o adimula oba
Teni kan ole gboju soke wo lailai
Arugbo ojo o agbalagba baba
Iwo orisun ibukun
Odo anu ti nshan titi
Akikitan ose o agbalagba la nla
Onile ologo alalede anu gboro mi ro
Atoba jaye o adimula oba
Arugbo ojo o agbalagba baba
Akikitan ose o agbalagba la nla
Onile ologo alalede anu gboro mi ro (x3)