![Arugbo Ojo](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/01/2D/rBEeM1fyBM6AZUELAAB3rvMEIak830.jpg)
Arugbo Ojo Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Arugbo ojo o iba re ore elese a fope fun o
Bi ko ba se pe oluwa ko ile na awon to kan se lasan
Gbope wa o jesu baba aleni boro
Arugbo ojo o iba re ore elese a fope fun o
Bi ko ba se pe oluwa ko ile na awon to kan se lasan
Gbope wa o jesu baba aleni boro
Opo ojo lo ti ro tile ti fimu
B’oluwa ba da o si ope lo ye ko ma fi fun ni gba gbogbo
Aanu oluwa po titi rani de ti okun lo
Arugbo ojo o iba re ore elese a fope fun o
Bi ko ba se pe oluwa ko ile na awon to kan se lasan
Gbope wa o jesu baba aleni boro
Ese eniyan ti to lati je ki oluwa di eti si wa
Alanu lolorun oba ti foju fo ese o
Oun lo ni kelese o wa a o fi isimi fun yi
Eyin ti e di eru ese to wuwo lelori ewa o
Arugbo ojo o iba re ore elese a fope fun o
Bi ko ba se pe oluwa ko ile na awon to kan se lasan
Gbope wa o jesu baba aleni boro
Iru olorun eyi emi o riri ninu oba
Ogbelese la oba ato ba jaiye ni
Ewo bo se seyanu femi nikan tan ewo ese baami dupe
Ore e wa e wa sin jesu e e
Ore mi duro doluwa a se ti e lasepe
Oun rere bayi o koma ni won nile gbogbo wa
Wait on the lord be of good courage
And jesus shall strengthen strengthen your heart
Wait on the lord be of good courage
And jesus shall strengthen strengthen your heart
baba wa ti be ni orun ki a bowo foruko re
Ki ijoba re de ife re tire ni ka sa laiye
Ife tire ni kase laiye bi won ti se ni orun
Fun wa lonje ojo wa dari ese wa jiwa
Bi wa tin dariji enikeji
Ma fawa sinu idanwo laiye o
Sugbon gba wa kuro ninu ibi
Nitori ijoba ni tire agbara ni tire ogo nitire
Lailai ati lai lai o
baba wa ti be ni orun ki a bowo foruko re
Ki ijoba re de ife re tire ni ka sa laiye o
Ife tire ni kase laiye o
Ife tire ni kase laiye o
Ife tire ni kase laiye o
Ife tire ni kase laiye o
Ife tire ni kase laiye o