![Kristi Apata](https://source.boomplaymusic.com/group2/M00/01/2D/rBEeM1fyBM6AZUELAAB3rvMEIak830.jpg)
Kristi Apata Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2013
Lyrics
Ara e a be ba bi mi ma ri s’oro
Omo adamu laiye eni se be to roka
Tasokun simu bi eni fi ounje
Iwa omo adamo ege
Moti duro le Kristi apata ile miran iyanrin ni
Mo je gbekele oun kan o eyin oruko la jesu
Aguntan ma sonu eni ti mi mo to le gba o oun ni
Jesu Kristi oba to ba gbokanle teniyan
Wa ja o pule won tu fi o seleya
Iwa omo adamo ewu
Moti duro le Kristi apata ile miran iyanrin ni
Mo je gbekele oun kan o eyin oruko la jesu
Alaja lo gbajare sun ara le o ki satani a kowo omo re baso
Tori eni to ba fowo kan omo oga ogo a jiya
Se mo pe eni ba jawe senu arija oodi mo so
Moti duro le Kristi apata ile miran iyanrin ni
Mo je gbekele oun kan o eyin oruko la jesu
Alagbawi eda laiye o
A funi ma sire gun
Irawo owuro omo maria gba mi mo de o
Ogbigba tin gbelese gbangbani