![Asoju](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/09/65d732d6475c425e9f9a3ddeea863450_464_464.jpg)
Asoju Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2016
Lyrics
Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Kalè jẹ́ asojú
Kalè jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa
Arabaribiti, Ọlọ́run Oba tó dá gbogbo aiye.
O fẹ́ràn ọmọ aráyé
ló bá f'ọmọ rè kan ṣoṣo fún wa
Láti gbà wa kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Égun òfin ti a gbà l'ọgba Édéni
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o, Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Nítorí ọjọ́sí O jiya o
Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí, Lọ́jọ́sí
Gbogbo wa lati sẹ̀ lati kùnà ògo Olúwa nitori ọjọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Nítorí ọjọ́sí O jiya o
Nítorí ọjọ́sí a fi rúbọ
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
Lọ́jọ́sí Lọ́jọ́sí o
O gbà wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìgbèkùn èsè
Kalè jẹ́ asojú
Kalè jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa
Ó tú wa sílẹ̀ kúrò nínú gbogbo ìdè ẹ̀sẹ̀
Kalè jẹ́ asojú
Kalè jẹ́ asojú rẹ̀
Kalè fi igbesi aiye wa fa ẹlẹsẹ wọ ìjọba ọ̀run
Kalè je asoju
Asoju ni wa
For we must all appear before the judgment seat of Christ
So that each one may receive what is due for what he has done in the body
Whether good or evil.
Ìmọ́lẹ̀ aiye lo yẹ ki a jé ̣
Kí a lè fi ọ̀nà han awọn elésè
Ti Ọlọ́jọ́ bá dé
Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa
Ka ma jèbi isẹ́ tó rán wa
Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o
Ọ̀dájú ọ̀dájú o, Ọ̀dájú ọ̀dájú o
A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa
To bá de to bá de o, to bá dé o o
Tó bá dé to bá de o, Tó bá dé to bá de o
To bá dé, To bá dé, To bá dé, To bá dé
A o jíyìn a o jere iṣẹ́ ọwọ́ wa
Tó bá dé tó bá de o, to bá dé o o
Tó bá de tó bá de o, Tó bá de tó bá de o
Se rere se rere o, se rere onigbagbo se rere o, se rere o
Se rere se rere o, Se rere se rere o
Oun bo