![Ogun ti se (Live) ft. Mercy Sunday & Enoch Oniyide](https://source.boomplaymusic.com/group10/M00/03/15/4f0b8ec20f3f48a0ad982d22c62765a8_464_464.jpg)
Ogun ti se (Live) ft. Mercy Sunday & Enoch Oniyide Lyrics
- Genre:Gospel
- Year of Release:2024
Lyrics
A naa a kologbe nitoriwa
A palara nitori irekoja awon ti a rapada
A jeniya atun ponloju
Ko ma s'ẹnu sọrọ kan
ina ti a naa ohun lafi muwa larada
larada o
Ogun se o
Ogun se o
Ogun se o
Olugbala ti segun fun mi
Oba ogo nbe ninu wa
K'alase ati alagbar'aiye wa gbọ ki won juba
Iwa ninu ife Olu
ko ma si eru fun wa mọ o
Hallelujah
ati ré iku koja sinu iye
Ogun se o
Ogun se o
Ogun se o
Olugbala ti segun fun mi
Ogun se o
Ogun se o
Ogun se o
Olugbala ti segun fun mi
Awaju asegun lo
Awaju asegun lo
Nitori Awa gbekewa le o Jesu
Ogun se o
Ogun se o
Ogun se o
Olugbala ti segun fun mi