![Ayanmo Ife](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/32/rBEeMVfyEkqACNU_AADZkrb3PYc103.jpg)
Ayanmo Ife Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Ololufe woju mi so fun mi e o fe mi
Ayanmo ife la je fun ra wa latodo enito da wa

Ofi imole're funmi ofagbara mi fun o
Ofi imole're funmi ofagbara mi fun o
O wa fi danu sinu wa lati mo fe lati more

Owo mi re fami daani ase olorun
Ayanmo ife laje fun ra wa latodo eni to da wa
Ayo wi dajo se ola wa to dajo ni
Irin wa ti dajo rin ibanuje ko jina si wa
Wo mi o tu mi wo pelu oju inu
Irin wa laye jo rawon
Wo mi o tu mi wo pelu oju inu
Irin wa laye jo rawon
Ayanmo wa jo ayanmo loro ife wa se se reji

Owo mi re fami dani ase olorun ni
Ayanmo ife laje fun ra wa latodo eni to da wa
Kolese ki ja ma wa jowo ja e jo saso ye
Boro ba se bi oro jowo fi suru ba mi se
Ore okan mi oemi o bi mi ojiri wa ko ma lanu

Baba fi imo wa sokan oke oke la o ma lo
Baba fi imo wa sokan oke oke la o ma lo
Owo mi re o fami dani ase oluwa ni
Ayanmo ife laje fun ra wa latodo eni to da wa
Ololufe woju mi so fun mi e o fe mi
Ayanmo ife la je fun ra wa latodo enito da wa
Ololufe woju mi so fun mi e o fe mi
Ayanmo ife la je fun ra wa latodo enito da wa
Ofi imole're funmi ofagbara mi fun o
Ofi imole're funmi ofagbara mi fun o
O wa fi danu sinu wa lati mo fe lati more
O wa fi danu sinu wa lati mo fe lati more
Owo mi re fami daani ase olorun
Ayanmo ife laje fun ra wa latodo eni to da wa
Bafefe idawo ba fe de duro timi o giri giri
Boti wun kki orun mu to sunmo dudu a wa dandan ni

Iwe nu mo ma lo je ka tun ri anu gba si ni
Isoro oni adun ola ni ayo atope loma jasi