![Imole Atan](https://source.boomplaymusic.com/group1/M00/01/32/rBEeMVfyEkqACNU_AADZkrb3PYc103.jpg)
Imole Atan Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2014
Lyrics
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Oro itunu latu fi ran mi de e sunmo mi ewa gbo
Oro ireti mo tun gbede e sunmo mi ewa gbo
Pelu imisi ni mo soro adeda lo ran mi wa
Iwo gangan loran mi si eti nu re mo fey a
Oni wi fun o igba ati asiko o be fun ohun gbogbo
Igba gbingbin igba kika igba kiko sogbo
Imola atan imole atan omo eniyan imole atan
Sugbon so mo imole on tan to ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Orisirisi eso lowa igba ototo lon de
Oni iru ero oko lowa igba ototo londe
Beeni orisirisi ogo ototo orisirisi ola ototo
Igba ototo lani okun pupa to pin ya odi jeriko to wo lule
Igba ototo ni won ko ma fi tabe bi we ti obe
Asiko ogora won adeda lo mo eto
Adeda lomo asiko owo re ma longbe
Imole atan m ye aju
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Ka biamo to gbomo jo odida dan ko gboyun
Eyin ro mi ibadi ro mi ko to di pe omo tuntun waye
Tita riro la kola bo jina tan lo doge
Ero re si o oun gbogbo lonje asiko loun gbogbo
Ninu oun gbogbo ka ma dupe ninu ire okan
Okuntun to su dede oro ologo lo ma mo
Imole atan owuro un bo imole atan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Okunkun to su oun olorun ni
Okunkun to su oun olorun ni
Imole atan imole a tan imole tan
Sugbon se mo pe imole o ni tan bi o ba fi dudu bora
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan
Eledumare lo mo ibi o mu ni le
Odi dandan leyin imole atan mo mo ye
Eda elo ni suru imole atan