
2:30 (Mixed) Lyrics
- Genre:Afrobeats
- Year of Release:2023
Lyrics
2:30 (Mixed) - Asake
...
Àwa dé, àwa dé-dé
Àwa l'ọmọ tọ ń sọ, ti o seke, ye
Orímọlade gbe mi de'bẹ
Jigan, jigan, ẹsẹ mi o de'lẹ, de'lẹ
Àlàyé mi, stop ṣe bẹ
O fẹ jẹ ń bi, o tún fẹ jẹ ń bẹ, ò pọ, sẹ
Agba-awo, f'ẹnu fo fence, sún s'ẹhìn
Àmọ 'rawa, ṣ'o get?
Abínibí yàtọ sí ability
Ẹ sọ̀ fún wọn t'oba tẹ'ri si, wọn má pa l'órí
T'ẹnu kọ, emi promising
Awọn tẹ fọ fun, fọ fun mi
Torí ko s'ẹlòmíì, many men fẹ dàbí mí, ẹ ri bi
Ẹ gbé Ọlọrun tóbi
Mo d'aṣọ ẹbi for my country
You can call me Mr. Money
Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ
Mm-mm-mm, mm-mm (ye-ye, ye)
2:30 fẹ lu (2:30 fẹ lu), oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ
Èrè mò bawa, ko si ija
Ṣòkòtò penpen, ye, àyé ni'ka
Yebo, yeba
Formulation lo gba, yeja
Ọmọ iyami, ko stay wise
Tranquillity, tranquillity
I no get time to dey form activity
Ko le kalas, I dey find stability
Like Abacha, money long, infinity
What's the chances, what's the probability
To see a better version of me with agility?
No, you can't fake reality
Ogun principalities and calamity
Mo ti lọ, mo ti pá 'yẹn ti
Bẹbẹ no dey for Jiji, o ṣí wa ń títí
Still get money like Fiti
Drippin' like Fiji, I be real G
Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ
Mm-mm-mm, mm-mm
2:30 fẹ lu, oya, ka turn up, ki'lẹ to mọ