- Genre:Highlife
- Year of Release:2022
Lyrics
Kadara 1 - Alhaja Aminat Obirere
...
ibanuje oni fi ile mi sebugbe ooo
Ekun aramoju oni fi ile mi sodede
Ibanuje ninu aye mi o to ge
Ibanuje oni fi ile mi sebugbe oooo
Beeni
Ekun aramoju oni fi ile mi sodede
Odede de ooo
Ibanuje ninu aye mi o to ge
Ibanuje oni fi ile me sebugbe ooooooo x2
Ekun aramoju oni fi ile mi sodede
Ibanuje ninu aye mi o to ge
Ibanuje oni fi ile mi sebugbe oooo
Komafisebugbe
Ekun aramoju oni fi ile mi sodede
Mo be e olorun
Ibanuje ninu aye mi o to ge